Single User Login finalisation announcement/Personal announcement

This page is a translated version of the page Single User Login finalisation announcement/Personal announcement and the translation is 50% complete.

Àkópamọ́ yín yíò jẹ́ títúnsọlórúkọ

Ẹ kúu lẹ̀,

Ẹgbẹ́ olùgbédìde Wikimedia únṣe àyípadà sí bí àwọn àkópamọ́ ṣe únṣiṣẹ́, gẹ́gẹ́bí ọ̀nà láti pèsè àwọn ohun àmúlò tó dára fún àwọn olùṣe wa bíi ìfúnlákìíyèsí káàkiri wiki. Àwọn àyípadà yìí túmọ̀ṣí pé àkópamọ́ yín gbọ́dọ̀ jẹ́ ọ̀kannáà káàkiri. Yíò gbà wá láyè láti fún yín ní àwọn ohun àmúlò tuntun tí yíò ràn yín lọ́wọ́ láti ṣàtúnṣe àtí fọ̀rọ̀jomitoroọ̀rọ̀ dáadáa, àti tí yíò jẹ́ kí ìgbàláyè àwọn olùṣe sí àwọn àmúlò ó ṣe é ṣe. Èyí túmọ́sí pé àwọn àkópamọ́ olùṣe gbọ́dọ̀ jẹ́ ìkannáà káàkiri gbogbo àwọn wiki 900 Wikimedia. Ẹ wo ìpoloungo fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.

Unfortunately, another person is using your same username, "{{subst:PAGENAME}}", elsewhere. To make sure that both of you can use all Wikimedia projects in future, we have reserved the name {{subst:PAGENAME}}~{{WIKI}} that only you will have. If you like it, you don't have to do anything. If you do not like it, you can choose a different name.

Your account will still work as before, and you will be credited for all your edits made so far, but you will have to use the new account name when you log in.

Sorry for the inconvenience.

Yours,
Keegan Peterzell
Community Liaison, Wikimedia Foundation