Fundraising 2012/Translation/AdrianneW Appeal/yo

This page is a translated version of the page Fundraising 2012/Translation/AdrianneW Appeal and the translation is 40% complete.

1

O pe die ki n to ka iwe naa tan nitori o tobi pupo sugbon mo feran iwe naa gan-an.Ni kilaasi karun-un, awon oluko wa so wipe ki a yan akori eyikeyii ti a ba fe, ki a si se alaye kikun lori re fun awon akekoo egbe wa. Mo yan lati salaye nipa litireso orundun kerindinlogun

Today, as you probably guessed, I’m an English professor. I also contribute to Wikipedia, editing articles about writers like Mary Shelley, the author of Frankenstein, and Jane Austen, who wrote Pride and Prejudice.

Nigba ti mo ba ronu lori ise ti mo n se fun wikipedia,mi kii ka aa mi si eni ti o kan n se afikun lasan, Mo ka ara mi si Oluko kan. Nispase wikipedia, mo maa n kan iye awon eniyan ti o po ju iye awon akekoo mi ni ile iwe. Ni osu ti o koja nikan, won ti ka apileko nipa jane Austen ni igba egberun lona aarundinlogofa.

At my university, I have access to many quality resources. But most people can't access these sources; they’re hidden behind a paywall. By editing Wikipedia, I can help fix this injustice.

I love learning. I always have. Which is why I believe so strongly that it should be available to everyone.

Do you agree? Then please join me in supporting Wikipedia.

Bio

Adrianne’s research is focused on 18th century British literature.

Ise Dokita Adrianne da le iwadii nipa Litireso Geesi ni Orundun Kerindinlogun. Leyin ti o ti gba oye Ph.D, o tun maa n se iwadii nipa Kikekoo ati sise iwadii lailo iwe ti a le fi oju ri tabi f’owo kan. O tun maa n ran awon oluko egbe re lati wa awon ona tunutun ti won le fi maa fi Wikipedia ran awon akekoo won lowo n’ile iwe.