Fundraising 2012/Translation/Erlan Vega video (captions)/yo

This page is a translated version of the page Fundraising 2012/Translation/Erlan Vega video (captions) and the translation is 55% complete.

1 00:00:00,500 --> 00:00:04,497 Mo je Oluko ede Geesi. Mo ti segbeyawo, Mo si ni Omo Obinrin Kan.

2 00:00:05,200 --> 00:00:13,587 Mo no ise ounje oojo bii ti awon eeyan miiran. Mo ni itoleseese ojoojumo. Momaa n lo si ibi ise mo si ma n pada s'ile.

3 00:00:14,192 --> 00:00:20,443 Mo ni aini bii ti awon elomiran, mo si tun maa n fe lati lo akoko ti mo ba ni lori Wikipedia

4 00:00:20,500 --> 00:00:23,943 Oruko mi ni Erlan Vega. mo n gbe ni La Paz, Bolivia.

5 00:00:23,943 --> 00:00:32,610 Mo maa n ko aroko nipa orisirisi nnkan, awon eranko bi Labalaba, awon Kokoro ati awon eran igbo.

6 00:00:33,000 --> 00:00:39,130 Ni Bolivia, awon eeyan kii saba kowe sile, Won kii kowe, won kii sii fe se ohun tuntun.

7 00:00:39,750 --> 00:00:45,936 Won kan maa ko awon imo s'ori, won a si koo sile nigba idanwo

8 00:00:46,850 --> 00:00:50,040 Ti won ba beere ibeere nigba miiran, o maa da bi eni wipe looto ni won fe mo ohumn ti won beere ti won si fe fii silo

9 00:00:50,040 --> 00:00:53,480 O maa wa n dabi igba ti won ba bi akekoo no opo ibeere nigba idanwo

10 00:00:53,480 --> 00:01:00,876 ti akekoo naa ko ri ohunkohun ko sile nitori ko tii si iwe re yewo ri lati igba ti eko ti bere

11 00:01:01,310 --> 00:01:08,501 fifun eni kan ni anfaani lati se nnkan tuntun ati lati mo ohnu ti won ko tii mo tele

12 00:01:11,210 --> 00:01:13,855 ti je oan nini awon ohun to yi igbesi aye mi pada si daradara

13 00:01:14,458 --> 00:01:19,892 Gbogbo re bere nigba ti mo lo si Wikitionary, iyen iwe atumo ede ti Wikipedia lojo kan

14 00:01:19,892 --> 00:01:25,360 vamo ba omobinrin yii pade , oruko inagije re ni Dabawdygirl Awa mejeeji n ba eni kan ti o maa n ba ayika je ja lori intaneeti

15 00:01:26,200 --> 00:01:34,570 O wa fe ba mi soro ni ede sipeeni, sugbon ko ja gaara

16 00:01:35,022 --> 00:01:41,250 awa mejeeji we se adehun ti ko ni akosile wipe a maa ko ara wa ni ede onikaluku

17 00:01:41,246 --> 00:01:48,130 a wa bere nipa sise atunse si kudie-kudie ti onikaluku ni a si tun ko ede nipa lilo wikitionary

18 00:01:48,583 --> 00:01:53,510 nigba to ya Geesi mi bere si ja gaara nitori mo maa n kaa lojoojumo

19 00:01:54,765 --> 00:01:56,950 Nigba ti mo fi maa pari eko ede Geesi mi

20 00:01:56,946 --> 00:02:09,180 Mo yege ninu idanwo ECP eyi ti Ijoba so di dandan fun awon Oluko Eyi si je ki n ri ise oluko gba

21 00:02:09,180 --> 00:02:13,480 ati wipe maaki ti mo gba ninu idanwo ECP to eyi ti won n fe fun ise oluko

22 00:02:14,010 --> 00:02:19,570 And they started some training, and I have been working there for five years now.

23 00:02:21,790 --> 00:02:29,090 It's amazing because of that I have the stability, I got married. I have a daughter, so Wikipedia has changed my life.

24 00:02:29,273 --> 00:02:29,420 Director: Victor Grigas Codirector: David Grossman

25 00:02:29,273 --> 00:02:32,570 (cc-by-sa 3.0 tag needed here)

26 00:02:29,422 --> 00:02:29,660 Producer: Zack Exley Director of Photography: Pruitt Y. Allen

27 00:02:29,659 --> 00:02:29,910 Video Photographers: Jack Harris, Adam Parr, Matthew Storck

28 00:02:30,173 --> 00:02:30,770 Portrait Photographers: Adam Novak, Karen Sayre

29 00:02:30,767 --> 00:02:31,190 Makeup: Melissa Klein

30 00:02:31,190 --> 00:02:31,980 Interviewers: Alma Chapa, Jonathan Curiel, Stephen Geer, Dan McSwain, Corey O'Brien, Frank O'Brien, Jacob Wilson

31 00:02:31,979 --> 00:02:32,650 Production Coordinators: Megan Hernandez, Bryony Jones, Beatrice Springborn

32 00:02:32,648 --> 00:02:33,090 Production Assistants: Toby Hessenauer, Kristin Rigsby

33 00:02:33,091 --> 00:02:33,510 Production Assistants: Toby Hessenauer, Kristin Rigsby

34 00:02:33,509 --> 00:02:33,880 Writer: Desirina Boskovich

35 00:02:33,883 --> 00:02:34,490 Transcription Services: Kate Aleo, Michael Beattie, Karen Callier, Petro Leigh, Mimi Li, Jacqui Pastor, Kristie Robinson, Brittany Turner, Susan Walling

36 00:02:34,487 --> 00:02:34,990 English Closed-Captioning: AlanKelly VerbatimIT

37 00:02:34,992 --> 00:02:35,420 [...]