Wikimedia Foundation elections/2021/2021-06-09/Call for Candidates/yo

This page is a translated version of the page Wikimedia Foundation elections/2021/2021-06-09/Call for Candidates and the translation is 80% complete.
Outdated translations are marked like this.

The election ended 31 Oṣù Kẹjọ 2021. No more votes will be accepted.
The results were announced on 7 Oṣù Kẹ̀sán 2021. Please consider submitting any feedback regarding the 2021 election on the elections' post analysis page.

Ẹ n lẹ́ níbẹ̀ yẹn oo,

2021 Board Elections
Main Page
Candidates
Voting information
Single Transferable Vote
Results
Discussions
FAQ
Questions
Organization
Translation
Documentation
This box: view · talk · edit

Ìdìbò síÌgbìmọ̀ Amúṣẹ́ṣe ti ọdún 2021 ń bọ̀ láìpẹ́. Gbogbo ẹni tí ó bá peregedé tí ó sì nífẹ́ láti díje sípò ni ó ní ànfaní láti forúkọ sílẹ̀.

Ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe ti àjọ Wikimedia ni wọ́n ń ṣe àbójútó sí iṣẹ́ àjọ Wikimedia ọláọ́kan-ò-jọ̀kan. Gbogbo àwọn tí a bá ṣàyàn tàbí dìbò fún láti dupò náà ni wọn yóò lo sáà ọdún mẹ́ta gbáko nínú ìgbìmọ̀ náà. Gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ Wikimedia lágbàáyé ni wọ́n ní ànfaní láti fìbò yan ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá fọkàn tán tí wọ́n sì ri wípé ó peregedé sí ipò ìgbìmọ̀ náà.

Dídìbò fún àwọn olùdíje tí a fẹ́ ni yóò mú ìṣọ̀kan àti ìṣojú gbogbo ẹ̀yà dúró ṣinṣin nínú ìṣeẹ́ wa.

Àwọn wo ni wọ́n lè díje? Ṣe o peregedé létí díje bí?

Àwọn ìṣesí tí a ń retí

Gẹ́gẹ́ bí àjọ Wikimedia ṣe jẹ́ àkójọpọ̀ gbogbo ẹ̀yá jákè-jádò agbáyé, bẹ́ẹ̀ náà ni a ṣe ń retí ìmọ̀ ọ̀tun, ọgbọ́n àtinúdá àti èrò itẹ̀síwájú, ìwà ìrẹ̀lẹ̀ àti ibọ̀wọ̀ fúni pẹ̀lú imọ̀ nípa iṣẹ́ ọlọ́ka-ò-jọ̀kan tí àjọ Wikimedia gbé dáni lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ díje dupò ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe ti àjọ Wikimedia. Yóò jẹ́ ohun tí ó ṣe pàtàkì kí àwọn àwùjọ tí wọn kò fi bẹ́ẹ̀ gbajúmọ̀ náà ó yan aṣojú wọn pẹ̀lú sínú ìgbìmọ̀ náà kí wọ́n Ma ba wà lẹ́yìn mọ́.

Ìfọkànsìn

Gbogbo ọmọ ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe ni wọ́n ní ànfaní láti lo ọdún mẹ́ta láti fi ṣe iṣẹ́ tí wọ́n gbà, bákan náà ni wọ́n sì tún lè tún wọn yan sípò náà lẹ́mẹ́ta ọtọ̀ ọ̀tọ̀. Àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ náà yóò ma lo wákàtí 150 láàrín ọdún kan láti fi ṣiṣẹ́ tàbí ṣe ìpàdé, nígbà tí a kò ṣí àsìkò tí wọ́n bá fi rin ìrìn-àjò mọ. Ẹ lè wo one of The Board committees fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé.

Àwọn ohun àmúyẹ

Èdè Gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n fi ń ṣiṣẹ́ nínú ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe yí, a nírètí wípé ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ díje sípò ìgbìmọ̀ yí gbọ́dọ̀ gbọ́ tàbí Mọ èdè Gẹ̀ẹ́sì í sọ, bí ó tilẹ̀-jẹ́ wípé wọn yóò ma ṣe ìdánilẹ́kọ́ lórí èdè Gẹ̀ẹ́sì fún àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ bí ó bá yá. Wọn yóò si ma ṣe ògbufọ̀ Ìforúkọsílẹ̀ gbogbo Òndíje sí èdè orisirisi pẹ̀lú.

'Forúkọ sílẹ̀:

Ẹnikẹ́ni tí ó bá lérò wípé òun peregedé láti díje ni a ń retí, bákan náà bí ẹ bá mọ ẹnikẹ́ni tí imọ̀ rẹ̀ kún tó láti díje, ẹ gbàá níyànjú kí ó díje. Gbogbo olùdíje lè forúkọ sílẹ̀ ní ibí: Forúkọ sílẹ̀ láti díje

Ẹ ṣeun púpọ̀,

Ìgbìmọ̀ Amúṣẹ́ṣe Àjọ Wikimedia