Wikimedia Foundation Board of Trustees/Call for feedback: Board of Trustees elections/Call for Feedback about the Board of Trustees elections is now open/Short/yo
Ìpè fún èrò lórí ètò ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti sí sílẹ̀
Ìpè fún èrò: Ètò ìdìbò fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti sí sílè, yí ò sì wá só pìn ní 7 February 2022.
Pẹ̀lú ìpè fún èrò yìí, ẹgbẹ́ Strategy Àjọṣepọ̀ àti Governance n gba ọ̀nà míràn yọ. Ọ̀nà yìí o ṣe àgbérò àwọn èrò ará láti 2021. Dípò ṣíṣe ìdarí pẹ̀lú àwọn àbá, ìpè yìí o tẹ̀lé ìlànà àwọn ìbéèrè gbòógì lát’ọ̀dọ̀ fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́. Àwọn ìbéèrè gbòógì yìí wá lát’orí àwọn èrò ti ètò ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ 2021. À ngbèrò láti ṣe ìwúrí fún ìjíròrò àti ìdàgbàsókè àbá lórí àwọn ìbéèrè wọ̀nyí.
Ó dìgbà,
Movement Strategy and Governance