Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí/Àwọn ìlànà Ìgbófìnró
Ìlànà Ìgbófìnró UCoC
These are the enforcement guidelines produced by the Universal Code of Conduct Phase 2 drafting committee. The text has been approved by the community. Comments can be made on the talk page and at local discussions. Please do not edit this section directly. |
Enforcement guidelines summary
In this table, you can find a summary of the full Enforcement guidelines. It was created to ensure that every member of the community can understand the new guidelines.
WHO is responsible for enforcing the UCoC?
- Designated community functionaries and bodies[1]
- The Wikimedia Foundation
- Event safety team members and people in similar roles
- A new committee called the Universal Code of Conduct Coordinating Committee (aka the U4C)
- The U4C will monitor enforcement of the UCoC. The composition of the U4C will be decided by the U4C Building Committee. The building committee will be selected in the same way as the previous UCoC committees. The outline prepared by the Building Committee will be voted on by the community
Local and global functionaries should understand how UCoC enforcement works even if they are not part of the U4C
- Notes
- ↑ such as, but not limited to administrators or Arbitration Committees
HOW will this be done?
- The UCoC should be visible in as many places as possible
- Certain individuals will have to declare their regard for and adherence to the UCoC
- Local communities, affiliates, and the Wikimedia Foundation should develop and conduct training for community members so they can better address harassment and other UCoC violations
- The guidelines also lay out recommendations for which parties should address what types of UCoC violations
- The guidelines suggest certain principles for processing and filing cases to ensure UCoC violations are addressed similarly across all projects
- The Enforcement Guidelines represent the boundaries of the kinds of behaviour communities should engage in to enforce and follow the UCoC
WHAT additional things need to be in place for this to happen?
- The Enforcement Guidelines recommend the creation of a centralized reporting system
- Communities are free to continue to use their existing enforcement systems as long as they do not contradict the Enforcement Guidelines
- The Enforcement Guidelines note that appeals should be possible and practically available to individuals who were sanctioned for UCoC violations
Àkótán
Ìtúmọ̀ Ètò Ìgbófinró
Ètò Ìgbófìnró ni ìdènà, ìṣàwàrí, ìwádìí, àti àwọn ìgbésẹ̀ míràn láti dáhùn sí àwọn ìwà tí ó tako Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí.
Ètò Ìgbófìnró jẹ́ ojúṣe àwọn àlákoso tótọ́ àti àwọn ẹgbẹ́ pẹ̀lú ohun-èlò àmúyẹ tàbí tó lágbára, bíi: àwọn syop, steward, ArbCom ìbílẹ̀ àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn, àwọn aláàbò àpèjọ, Ìgbìmọ̀ elétò Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí (U4C), àti Wikimedia Foundation.
Àwọn ará ìbílẹ̀ lè yan àwọn alákóso, ní gbà tí ó bá yẹ, ní tí tẹ̀ lé òfin iṣẹ́-pínpín wípé àwọn ará orí wiki atí ojú-ayé gbọ́dọ̀ ṣe ìpinnu láàrín ara wọn nígbà tí ó bá ṣeéṣe.
A gbọdọ̀ ṣeléyí ní pípé, kánkán, àti ní dédé káàkiri Àjọṣepọ̀ Wikimedia. Nítorínáà, àwọn ènìyàn tí a fi lé lọ́wọ́ láti gbé òfin Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí ró, wọ́n gbọdọ̀ mọ òfin náà dójú ìwọ̀n.
Ìgbófìnró UCoC yí ò wáyé nípa iṣẹ́ ìdènà àti ìpolongo, ṣíṣe àwọn ìkìlọ̀ láti pàrọwà fún àwọn ènìyàn tó ní ìwà àìbójúmu láti tèlé òfin, atún lè fi ìjìyà tó tọ́ jẹ irú ẹni bẹ́ẹ̀, tàbí àwọn ìgbésẹ̀ míràn tí ó yẹ. Àwọn alákóso kárí-ayé àti ìbílẹ́ tó ngbé àwọn òfin àti ìlànà ró lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia gbọdọ̀ ní ìmọ̀ lórí ètò àti ìlànà ìgbófìnró yìí.
Iṣẹ́ ìdènà (àròkọ 1 àti 2 UCOC)
Ìdí fún iṣẹ́ ìdènà ni láti mú kí àwọn oníṣẹ́ lórí àwọn wiki Wikimedia Foundation àti àwọn iṣẹ́-àkànṣe míràn tí UCOC tabá mọ̀n wípé òfin náà wà, àti pípolongo fún ìgbọràn àtinúwá.
Ṣíṣètò àwọn ìtúmọ̀ fún ìlànà ìgbófìnró UCoC
Ìlànà ìgbófìnró UCoC ojúlówó wà ní èdè gẹ̀ẹ́sì. A ó ṣe ìtúmọ̀ rẹ̀ sí àwọn èdè iṣẹ́-àkànṣe míràn. Ní ìgbà tí ìyàtọ̀ bá wà láàrín ìtúmọ̀ ọ̀rọ̀ ti ède gẹ̀ẹ́sì ojúlówó àti èdè míràn, ọ̀rọ̀ inú ojúlówó ni yí ò borí ìgbésẹ̀.
Ìmúdájú UCoC láàrín àwọn ẹgbẹ́ kan
UCoC yí ò tabá ẹnikẹ́ni tí ó nṣe àfikún sí àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia lórí ayélujára tàbí ní ojúkojú, àti àwọn ààyè tí a ṣètò lórí àwọn pẹpẹ ìta. Àwọn ènìyàn tí a ti tòjọ yìí gbọdọ̀ pinnu (nípa títọwọ́ bòwé àdéhùn tàbí ọ̀nà míràn) láti tẹ̀lẹ́ Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí:
- Gbogbo òṣìṣẹ́, ará Ìgbìmọ̀ Onígbọ̀wọ́, àti agbaṣẹ́ṣe Wikimedia Foundation;
- Àwọn oníṣẹ́ tó ní àwọn ohun èlò alákòso;
- Àwọn ará tó bá wà láàrín ẹgbẹ́ ìgbófìnró iṣẹ́-àkànṣe Kankan;
- Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ lo àwọn ohun ìdánimọ̀ Wikimedia Foundation fún àwọn ìpàdé, iṣẹ́-àkànṣe, asojú, ẹgbẹ́ àjọṣepọ̀, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ;
- Ẹnikẹ́ni tí ó nwá iṣẹ́ ẹ̀ka Àjọṣepọ̀ Wikimedia lórí ayélujára tàbí ojúkojú (bí àpẹẹrẹ, ènìyàn tàbí ẹgbẹ́ tó fẹ́ polongo ìpàdé, ìgbìmọ̀, tàbí Ìwádìí tí Wikimedia ti ṣètò).
The users listed above should accomplish the affirmation at the occasion of acquiring the right or role, as well as every re-election, renewal or prolongation, the existing ones do so within a short time after the ratification of these guidelines, with exception of current advanced rights holders with rights that are not up for renewal who will not have a set timeframe to accomplish these affirmations. This may be changed on review after a year following the ratification of these guidelines. Once formed, the U4C will create procedures to facilitate these affirmations.
Àbá fún ìdánilẹ́kọ̀ UCoC fún àwọn ará àjọṣepọ̀
Kí Wikimedia Foundation ṣ’ètò àti ìdàgbàsókè ìdánilẹ́kọ̀ fún àwọn ará àjọṣepọ̀, pẹ̀lú ìmọ̀ràn lát’ọ̀dọ̀ àwọn ará àti ẹ̀ka àjọṣepọ̀, láti mọ̀, dáhùn, àti dẹ́kùn àwọn ìpalára tí ìtako UCoC yí ó fà, ní pàtàkì jùlọ ìyọlẹ́nu àti wàhálà ìwà wíwù míràn.
Àwọn ènìyàn tí ó yẹ kí ó mọ̀n àti kí ó tẹ̀lé Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí yí ó gbọdọ̀ lọ sí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ láti ríi dájú wípé òye tó gbòòrò wà lórí ìgbófìnró. Awọn ará àjọṣepọ̀ lè wá sí ìpàdé ìdánilẹ́kọ̀ yìí tí ó bá wù wọ́n.
È̩kọ́ fún àwọn oníṣẹ́ yẹ kí óní, àwọn ìlànà àti ohun èlò fún ìdánimọ̀ àwọn ìwà àíbójúmu àti ìlànà lórí ìdáhùn sí irú àwọn ìwà bẹ́ẹ̀.
È̩kọ́ yìí yẹ kí ó ní àwọn ipele ìwé-ẹ̀rí wọ̀nyí ókéré jù:
- Ipele àkọ́kọ́: Àkópọ̀ ìmọ̀ lórí UCoC
- Ipele ìkéjì: Ipá láti dáhùnsí rírú òfin UCoC
- Ipele ìkẹ́tàa: Ipá láti dáhùnsí ẹ̀jọ́ UCoC
- Ipele ìkẹ́rìn: Àtìlẹ́yìn fún àwọn olùfaragba ìyọlẹ́nu ní ọ̀nà tí óyẹ
Níní ìwé-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ kọ̀ túmọ̀ sí níní àṣe ìwọ̀n ìgbẹ́kèlé láti ṣe àwọn iṣẹ́ tí akọ́ nínú àwọn ẹ̀kọ́ náà.
- Àwọn ohun-èlò ìtúmọ̀ tí Wikimedia Foundatio yí ó pèsè nígbà tí ìjábọ̀ bá wá ní èdè tí àwọn ìgbìmọ̀ kò mọ̀ dáradára
- È̩kọ́ fún àwọn onísé àti òsìsé, tí Wikimedia Foundation s'ètò pèlú àtìléyìn àwon alákòso, láti kọ́ ìlànà ìwádìí àti òye UCoC ní ìse
Ṣíṣe ìpolongo fún UCoC
Láti fún UCoC ní ìrí, ìtọ́kasí sí ojú-ewé UCoC gbọdọ̀ wà lórí:
- Àwọn ojú-ewé ìforúkọsílẹ̀;
- Ojú-ẹsẹ̀ àwọn iṣẹ́-àkànṣe àti ojú opon àtúnse síse;
- Àwọn ojú-ewé ìfipamọ́ àtúnṣe fún àwọn oníṣẹ́ tí kò wọlé sórí iṣẹ́-àkànṣe pẹ̀lú ìdánimọ̀;
- Ojú-ẹsẹ̀ àwọn ojú-ewé ayélujára àwọn ẹ̀ka Wikimedia;
- Ìfihàn lórí àwọn ìpàdé ojúkojú;
- Àwọn ibò míràn tí ó yẹ fún àwọn iṣẹ́-àkànṣe ìbílẹ̀
Iṣẹ́ ìdáhùn (àròkọ 3 UCOC)
Ìdí fún iṣẹ́ ìdáhùn ní láti pèsè àwọn ọ̀nà fún gbígbàsílẹ̀ àwọn ẹ̀sùn, pípèsè àwọn ohun-èlò fún ìwádìí àwọn ẹ̀sùn, ìtúmọ̀ àwọn oríṣiríṣi òfin rírú àti ìlànà ìgbófìnró, pẹ̀lú àwọn àba lórí àwọn ohun-èlò ìfẹ̀sùnkàn, àti ọ̀nà fún ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn.
Ìpìlẹ̀-òye fún gbígbàsílẹ̀ àti ìwádìí àwọn ẹ̀sùn òfin rírú
Àwọn ọ̀nà ìgbẹ́jọ́ lọ sókè
- Olùfaragba ìyọlẹ́nu àti ẹni tómọ̀ nípa rẹ̀ ni ó lè fi ẹ̀sùn rírú òfin UCoC kàn;
- Agbọdọ̀ gbé ẹ̀sùn lọ sí òkè níbi tí ó bá ti yẹ, gégé irú òfin tí wón rú àati ònà ìgbófìnró;
- A lè fi àwọn ẹ̀sùn míràn sípò pàtàkì nígbà tí ó yẹ.
Ìlànà fún ìdáhùn
- Agbọdọ̀ yanjú àwọn ẹ̀sùn tí kò tóhùn kan ní ìlànà ìbílẹ̀ iṣẹ́-àkànṣe nípa ìkìlò tàbí ìfìyà jìjẹ, dípò ètò UCoC.
- Agbọdọ̀ yanjú àwọn ẹ̀sùn pèlú ònà òye.
- Agbọdọ̀ yanjú àwọn ẹ̀sùn ní àkókò tí ó yẹ.
- Ìgbìmọ̀ ìgbófìnró gbọdọ̀ ké sí àwọn olùkópa ẹ̀sùn tí ìwádìí náà yí ò bá pẹ́ẹ́.
- Irú ìyà tí a lè fi jẹ ẹni tó rú òfin UCOc yí ò dá lórí irú ojúṣe wọn (òṣìṣẹ́ tó ngbowó, oníṣẹ́ tí a dìbò fún tàbí yàn, olùfarajìn, etc.), bí wọ́n ti rú òfin náà, àti bí rírú náà ti ga tó.
- Àwọn tí ó n ṣe ìwádìí ẹ̀sùn ni kí ó pinnu bóyá ìwádìí ìkọ̀kọ̀ tàbí gbangba lóyẹ pẹ̀lú àgbéyẹ̀wò èrò ẹni tí ó fi ẹ̀sùn kàn.
Àwọn ẹjọ́ pàtàkì àti ìmúkúrò
- Agbọdọ̀ ju àwọn ẹ̀sùn tí kò tọ́ dànù, a sì gbodò dájó àwon tí ohun se eléyìí.
- Agbọdọ̀ yanjú àwọn ẹ̀sùn tí kò tóhùn kan ní ìlànà ìbílẹ̀ iṣẹ́-àkànṣe;
Pípèsè àwọn ohun èlò fún ìwádìí àwọn ẹ̀sùn
A lè ṣe àtìlẹ́yìn fún ìgbófìnró UCoC ní àwọn ọ̀nà oríṣiríṣi, tí àwọn ará àjọṣepọ̀ yí ò sì le yan irú àwọn ọ̀nà ní ìdálórí àwọn àmúyẹ tí wọ́n yàn, gẹ́gẹ́ bí ipá, ìwà wọn sí ìdarí, àti àwọn ohun tí àwọn ará fẹ́ràn jù. Lára àwọn àsàyàn ni:
- An Arbitration Committee (ArbCom) for a specific Wikimedia project;
- An ArbCom shared amongst multiple Wikimedia projects;
- Advanced rights holders enforcing local policies consistent with the UCoC in a decentralized manner;
- Panels of local administrators enforcing policies for a Wikimedia project; and
- Local contributors enforcing local policies through community discussion and agreement.
Kí àwọn ará túnbọ̀ máà ṣ’ètò ìgbófìnró ní àwọn ìlànà tó wà nlẹ̀ ní ìgbà tí wọn kò bá tako àwọn ìmọ̀ràn míràn lórí ìlànà yìí.
Ìgbífìnró gẹ́gẹ́ bí irú ẹ̀sùn
Abala yìí o ṣe ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àtòjọ àwọn onírúurú ẹ̀sùn òfin rírú, pẹ̀lú àwọn ohun èlò ìgbófìnró tó jọmọ́ wọn.
- Àwọn òfin rírú tó ní ìhàlẹ̀ ìjà ipá kankan
- Ojúuṣe Trust & Safety
- Àwọn òfin rírú tó ní ìhàlẹ̀ òfin àti ilé-ẹjọ́
- Agbọdọ̀ gbe irú àwọn ẹ̀sùn yìí lọ sí ẹgbẹ́ Legal Wikimedia Foundation, tàbí nígbà tó bá yẹ, àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n tó lè wo àwọn ànfààní ìhàlẹ̀ náà dájú
- Àwọn òfin rírú tó ní ìtú àsírí ohun ìdánimọ̀ ará
- Generally handled by users with oversight or edit suppression permissions
- Occasionally handled by Trust & Safety
- If the violation invokes a legal obligation, the case will be promptly sent to the Wikimedia Foundation Legal team or, when appropriate, other professionals who can appropriately evaluate the merits of the case
- Àwọn òfin rírú tó jọmọ́ ìdarí ẹ̀ka Wikimedia
- Ojúuṣe Affiliations Committee
- Ìjákulẹ̀ elétò láti tẹ̀lé UCoC
- Ojúuṣe U4C;
- Àwọn àpẹẹrẹ ìjákulẹ̀ elétò ni:
- Àìní ohun-èlò ìbílẹ̀ láti gbé òfin UCoC ró;
- Àwọn ìpinnu ìbílẹ̀ tó tako UCoC lóòrèkóòrè;
- Àìgbà láti gbé òfin UCoC ró;
- Àìní ohun-èlò tàbí ará láti dáhùn àwọn ọ̀rọ̀.
- Ojúuṣe U4C ni àwọn òfin rírú UCoC tó ré kọjá wiki ní ààyè àwọn alákóso
- Àwọn òfin rírú tí kò ṣẹlẹ̀ lórí wiki
(àpẹẹrẹ ni: àwọn ìpàdé ojúkojú tàbí ìjíròrò tí kò ṣ’ẹlẹ̀ lórí wiki tàbí àwọn ààyè tí àwọn pẹpẹ míràn ṣ’àmojútó ẹ̀)
- Existing local and global enforcement mechanisms like but not limited to : friendly space policies, rules of conferences, give the rules of behaviour and act in cases of off-wiki violations.
- Handled by the U4C where no local structure (eg. ArbCom) exists, or if the case is referred to them by event organizers, local affiliate groups, or the bodies that handle single-wiki UCoC violations. In some cases, it may be helpful to report the off-wiki violations to enforcement structures of the relevant off-wiki space. This should not be construed so as to imply that existing local and global enforcement mechanisms cannot act in cases of off-wiki violations.
- In instances of Foundation-hosted events, Trust & Safety provides event policy enforcement
- àwọn òfin rírú orí wiki
- Òfin rírú tó rékọjá àwọn iṣẹ́-àkànṣe: "Ìgbìmọ̀ U4C" yíò dáhùn tí àwọn alákòso ìbílẹ̀ tàbí àgbáyé kò bá dáhùn síi tàbí tí won bá pè wọ́n sí ẹ̀sùn náà;
- Àwọn òfin rírú UCoC lórí wiki kan: Àwọn ètò ìjọba ìbílẹ̀ iṣẹ́-àkànṣe kọ̀ọ̀kan ni yí ò dáhùn sí èyí ní ìtèlé ìlànà tí ó wà nlẹ̀
- Àwọn òfin rírú nínú àwọn ààyè ìmọ̀-ẹ̀rọ
- Ẹgbẹ́ Àlàkalẹ̀ fún Ìhùwàsí ti Ìmọ̀-ẹ̀rọ .
Àwọn Ìmọ̀ràn fún ohun-èlò ìfẹ̀sùnsùn àti ìwádìí
Láti jẹ́ kí ìfẹ̀sùnsùn àti ìwádìí àwọn òfin rírú UCoC túnbọ̀ ṣeéṣe, Wikimedia Foundation yí ó pèsè, yí ó sì ṣètọ́jú ohun èlò tó sọ̀kan fún fífẹ̀sùnsùn àti ṣíṣe ìwádìí lórí MediaWiki.
Àwọn ẹ̀sùn gbọdọ̀ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé láti jẹ́ kíí ẹjọ́ ṣeé dá àti láti pèsè àkọsílẹ̀ tó péye nípa ọ̀rọ̀ tó wà nlẹ̀. Lára àwọn àlàyé yìí ni:
- Ọ̀nà tí ìwà tí o fín sùn fi rú òfin UCoC
- Tani àti kíni òfin rírú UCoC yìí ṣe ìpalára fún
- Ọjọ́ àti àkókò tí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti ṣẹ̀;
- Àwọn ibi tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti ṣẹ̀;
- Àwọn àlàyé míràn tó wúlò fún àwọn ìgbìmọ̀ ìgbófìnró láti dájọ́ ọ̀rọ̀ náà.
Ohun-èlò yìí gbọdọ̀ ma nṣiṣẹ́ ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà ìlò-ìrọ̀rùn, ààbò fún ìdánimọ̀ àti ìpèsè fún ìwádìí àti ìjábọ̀ ìkọ̀kọ̀ àti gbangba:
Ààbò fún ìdánimọ̀
- Pèsè ààyè fún ìfẹ̀sùnsùn gbangba (tí àlàyé ọ̀rọ̀ náà yí ó wà fún gbogboògbò), tàbí ní ìkọ̀kọ̀ (bí àpẹẹrẹ, tí àwọn gbogboògbò kò ní mọ ìdánimọ̀ olùfẹsùnsùn; tí gbogboògbò kòní mọ ìdánimọ̀ àwọn ènìyàn tí ẹ̀sùn náà tabá; àti àwọn àpẹẹrẹ bí èyí);
- Gba àwọn oníṣẹ́ láàyè láti fẹ̀sùnsùn tí wọn kò bá tilẹ̀ wolé sóri wiki pẹ̀lú ìdánimọ̀
Ètò ìwádìí
- Pèsè fún ètò ìwádìí ìkọ̀kọ̀ fún àwọn ẹ̀sùn tí àwọn ìgbìmọ̀ ìgbófìnró yí ò dáhùn sí;
- Pèsè fún ààyè láti gbé àwọn ẹ̀sùn sókè sí àwọn ẹ̀ka tó tọ́; Tọ́ka àwọn ọ̀rọ̀ UCoC rírú tó nlọ lọ́wọ́ sí àwọn ọ̀rọ̀ ti tẹ́lẹ̀ tí ó kan oníṣẹ́ kanáà;
- Pèsè fún ọ̀nà láti so àwọn ìfẹ̀sùnsùn tí kò ṣẹlẹ̀ lórí ayélujára pẹ̀lú ètò ìfẹ̀sùnsùn kan;
- Jẹ́kí àwọn tí ó nṣe ìwádìí ọ̀rọ̀ ju àwọn ẹ̀sùn tí kò tọ́ nù
Ìjábọ̀ gbangba
- Pèsè fún ọ̀nà láti ṣ'àpamọ́ gbogbo ẹ̀sùn nígbangba láti ṣàwárí wọn, nígbàtí a sì tún pèsè ààbò ìdánimọ̀ fún àwọn ẹ̀sùn ìkọ̀kọ̀;
- Yan ìdánimọ̀ gbangba fún àwọn ẹ̀sùn kọ̀ọ̀kan fún ìdí ìṣàwàrí gbangba;
- Pèsè fún ìgba àlàyé sílẹ̀ lórí ìlò ohun-èlò yìí, fún ìdí ìjábọ̀ ìgbófìnró UCoC fún gbogboògbò, pẹ̀lú ọ̀wọ̀ fún ìdánimọ̀ àwọn ará àjọṣepọ̀ yìí
Kò pọn dandan fún àwọn ènìyàn tí a fún ní ojúṣe ìgbófìnró UCoC láti lo ohun-èlò yìí, wọ́n sìle tẹ̀síwájú láti lo àwọn ohun-èlò míràn tí wọ́n lérò wípé ó ṣiṣẹ́ náà dáradára, níwọ̀nìgbàtí wọ́n bá nṣe àwọn ìwádìí àti ìjábò ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà ìlò-ìrọ̀rùn, ààbò fún ìdánimọ̀ àti ìpèsè fún ìwádìí àti ìjábọ̀ ìkọ̀kọ̀ àti gbangba, kanáà.
Àwọn Ìmọ̀ràn fún àwọn ètò ìgbófìnró ìbílẹ̀
Níbi tí o bá ti ṣéeṣe, àn gbàníyànjú wípé kí àwọn ètò ìgbófìnró tó wà nlẹ̀ gbé ojúṣe ìgbàsílẹ̀ àti ìwádìí èsùn UCoC ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìlànà tí a ti là kalẹ̀. Ní àwọn ibi tí ètò ìgbófìnró ìbílẹ̀ báti múná ju òfin ìpelẹ̀sẹ̀ iwà lọ, a gbà ní’mọ̀ràn láti tẹ̀lẹ́ àwọn ètò ìgbífìnró tó wà nlẹ̀ dípò ìlànà yìí. Láti rí dájú wípé ètò ìgbófìnró wà ní ìdógba káàkiri àjọṣepọ̀, à ngba àwọn alákòso níyànjú láti lo àwọn ìmọ̀ràn tí ati là kalẹ̀ ní ìwọ̀n iṣẹ́-àkànṣe kọ̀ọ̀kan.
Ètò àìlójú ìṣájú
- Àwọn òfin ìdẹ́kùn ojú-ìṣajú tí yí ó ran àwọn alákòso àti àwọn míràn lọ́wọ́ láti séra tàbí yọwọ́ kúrò lórí ìjábọ̀ tí ọ̀rọ̀ náà bá tabá wọn. Ní ìdìmú àwọn ètò ìyanjú ọ̀rọ̀ tó wà nlẹ̀, ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá dárúkọ nínú ẹ̀sùn gbọdọ̀ yọwọ́ nínú ìwádìí ọ̀rọ̀ náà;
- Ní ìgbà tí a bá nílò àlàyé síbẹ̀ láti gbèjà ìpinnu U4C àti wíwà nínú òfin àti ìrètí ààbò fún ìdánimọ̀ àti dídẹ́kun ìyọnu fún olùfẹ̀sùnsùn tàbí ẹni tí à n fisùn ní ìtẹ̀lé ètò ìlànà, àwọn ẹgbẹ́ ìpinnu tó wà lókè yíò pè fún èrò ẹni tí à n fisùn.
Ìṣeyawọ́ ètò
- Àwọn ará Wikimedia àti/tàbí Wikimedia Foundation gbọdọ̀ pèsè ìjábọ̀ lórí ipọn àwọn onírúurú ìyọlẹ́nu tó wọ́pọ̀ tí a lè lò láti ṣ'àwọ̀rán àwọn ìdájọ́ oríṣiríṣi. Eléyì yí ó ràn àwọn alákòso tàbí àwọn ìgbìmọ̀ ìgbófìnró míràn lọ́wọ́ láti lo àwọn ìmọ̀ràn yìí láti pinnu lórí ipọn ẹ̀ṣùn
Wikimedia projects and affiliates, when possible, should maintain pages outlining policies and enforcement mechanisms in line with the UCoC policy text. Projects and affiliates with existing guidelines or policies in contradiction to the UCoC policy text should discuss changes to conform with global community standards. Updating or creating new local policies should be done in a way that does not conflict with the UCoC. Projects and affiliates may request advisory opinions from the U4C about potential new policies or guidelines.
Fún àwọn ìjíròrò lórí Wikimedia tí kò ṣẹlẹ̀ lórí wiki (bíi: Discord, Telegram, etc.), àwọn òfin ìlò Wikimedia kò dè wọ́n. Òfin àwọn pẹpẹ tí ìjíròrò náà ti nṣẹlẹ̀ ló dè wọ́n. Ṣùgbọ́n, a lè gba ìwà àwọn ará Wikimedia lórí àwọn pẹpẹ wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí nínú àwọn ẹ̀sùn òfin rírú UCoC. A dábàá pé kí àwọn pẹpẹ tí kò sí lórí wiki pèsè ìlànà tí yí ò dẹ́kùn gbígbé àwọn ìjíròrò orí wiki lọ sórí wọn.
Ṣíṣ’ètò ìgbẹ́jọ́lọsókè
Àwọn ènìyàn tí a bá rí tó ti rún òfin UCoC gbọdọ̀ ní ànfààní láti gbẹ́jọ́ wọn lọ sókè.
Àwọn ọ̀nà ìgbẹ́jọ́lọsókè
An action by an individual advanced rights holder should be appealable to a local or shared collective decision body other than U4C (such as an ArbCom). If no such collective decision-making body exists, then an appeal to the U4C can be permissible. Aside from this arrangement, local communities may allow appeals to a different individual advanced rights holder.
Ẹjọ́-kòtẹ́milọ́rùn kò ṣeéṣe ní àwọn ìgbà yìí:
- for vandalizing IPs, spam-only accounts, and similar cases
- for light sanctions (under 2 weeks ban)
- against a decision made by a Project’s community except if there is a suspicion of abuse of power or a systematic issue;
- against a decision of a high level decision making body except if referred by that body
- against certain decisions made by the Wikimedia Foundation Legal Team based on conflicting legal obligations
Deciding appeals by U4C and community bodies
Ìpinnu náà gbọdọ̀ dá lórí àwọn abùdà wọ̀nyí:
- Bí ìrú òfin UCoC àkọ́kọ́ ṣe le sí;
- Ìtàn ìrú òfin UCoC tẹ́lẹ̀ ní ọ̀dọ̀ ẹni tó rú òfin;
- Bí ìjìyà ẹni tí ó rú òfin ti le tó;
- Ipa tí ìrú òfin UCoC náà ní lórí àwọn ènìyàn, oníṣẹ́, àti iṣẹ́-àkànṣe náà ní àkótan;
- Ìwọ̀n ìgbà tí ìrú òfin UCoC ti ṣẹlẹ̀ sẹ́yìn;
- A lè ṣe ìtúpalẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ ìrú òfin náà àti gédégbe ọ̀rọ̀ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan bí ótiyẹ;
- Ìfura ìṣi àgbára lò; àti
- Ìfura ojú-ìsájú elétò.
Ìgbìmọ̀ elétò UCoC (U4C)
A ó ṣ’ẹ̀dá ìgbìmọ̀ àgbáyé titun tí à n pè ní Ìgbìmọ̀ elétò Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí (U4C). Ìgbìmọ̀ yìí yíò jẹ́ ẹlẹ́gbẹ́ pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ ìpinnu òkè míràn (àpẹẹrẹ: ArbCom àti AffCom), àti ìrọ́pò ìparí fún ìgbà tí ìjákulẹ̀ elétò bá wáyé lát’ọ̀dọ̀ ẹgbẹ́ ìbílẹ̀ ní ìgbófìnró Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí.
Ìwúlò
The Universal Code of Conduct Coordinating Committee monitors reports of breaches of the UCoC, may engage in additional investigations and will take actions to where appropriate. The U4C will regularly monitor and assess the state of enforcement of the Code and may suggest suitable changes to UCoC to the Wikimedia Foundation and the community for consideration. When necessary, the U4C will assist the Wikimedia Foundation in handling cases.
Ìgbìmọ̀ elétò Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí:
- Ṣe ìdáhùn sí àwọn ẹ̀sùn àti ẹjó-kòtẹ́milọ́rùn ní àwọn ipò tí a là kale, pẹ̀lú àwọn ìwádìí tí ó bá pọn dandan láti yanjú wọn;
- pèsè àwọn ohun-àmúlò tó yege fún àwọn ará láti tẹ̀lé UCoC, bíi àwọn ìwé ìdánilẹ́kò àti ṣíṣe àlàyé àwọn ìlànà ìgbẹ́jọ́lọsókè;
- together with high level decision making bodies and communities, provides a final interpretation of this document "UCoC Enforcement Guidelines" and the UCoC itself whenever ambiguity arises;
- Ṣíṣ’ètò ìlànà-àgbéyẹ̀wò / ètò àgbéléwọ̀n lórí àwọn ìpinnu àti àwọn ọ̀na láti ṣ’àtìlẹ́yìn fún ètò ìpinnu ṣíṣe lórí àwọn ẹ̀sùn;
- monitors and assesses the effectiveness of UCoC enforcement in practice and suggests changes amendments to the UCoC enforcement guidelines to align with future needs and concerns, with input from the Wikimedia Foundation and the broader community – makes suggestions to the Wikimedia Foundation and the community for changes to this document "UCoC Enforcement Guidelines" and the UCoC itself.
U4C fún ra rẹ̀ kòle:
- Ṣe ìyípadà sí ọ̀rọ̀ “Àwọn lànà Ìgbófìnró UCoC” yìí tàbí UCoC fún ra rẹ̀;
- ṣe ìdásílẹ̀ àwọn òfin tí yíò tako ọ̀rọ̀ “Àwọn lànà Ìgbófìnró UCoC” yìí tàbí UCoC fún ra rẹ̀, tàbí ṣe àgbéfò wọn ní ònà k'ọnà;
The U4C will not take cases that involve employer-employee relations disputes, general disagreements between the WMF and its affiliates, or any matter that does not relate to the violations of the Universal Code of Conduct, and its enforcement.
Àlàà ọ̀rọ̀
Àwọn àlàà wà fún irú àwọn ẹ̀sùn tí a lè gbélọsókè fún àgbéyẹ̀wò U4C.
U4C yíò ní àlàà fún ètò ìpinnu ìparí:
- Níbi tí kò bá ti sí àwọn ohun-èlò ìbílẹ̀ láti dáhùn ẹ̀sùn;
- Níbi tí kò bá sí àwọn ohun-èlò ìbílẹ̀ láti se ìwádìí ọ̀rọ̀;
- Níbi tí àwọn ohun-èlò ìbílẹ̀ fún ra wọn ti ṣe ìgbélọsókè ọ̀rọ̀ sí U4C láti yanjú;
- For severe systematic issues, that cannot be handled by existing enforcement structures, such as, but not limited to, cases of local structures counteracting the UCoC, UCoC violations spanning multiple Wikimedia communities or projects, or cases involving a large number of individuals. The U4C itself or the U4C building committee will impose detailed rules for acceptance of such cases.
- Níbi tí Wikimedia Foundation bá ti gbé ọ̀rọ̀ lọ bá U4C, tí U4C sì gbà láti yanjú ẹ̀
U4C le yàn aṣojú ìpinnu ìparí, àfi ní àwọn ìgbà tí àwọn wàhálà elétò wà.
U4C yíò tún:
- Ran àwọn ohun-èlò ìbílẹ̀ lọ́wọ́ lóri Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí. Lára rẹ̀ ni
- ìdánilẹ́kọ̀ọ́
- Dídábà àwọn iṣẹ́ tí ó dára
- àmọ̀ràn àti ìkànsí
- ríran ohun-èlò ìbílẹ̀ lọ́wọ́ láti ṣ’ètò ìgbìmọ̀ ìpinnu tó ní pan
- Provide reports to the global community and the WMF Board, no less than once a year, on UCoC enforcement, details of reporting will be decided by the U4C Building committee
- Dídábà àwọn àtúnṣe sí UCoC àti ìgbófìnró UCoC
- Ṣisẹ́ gẹ́gẹ́ bíi alájọṣe ará fún Wikimedia Foundation lórí Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí.
- Pèsè ìmọ̀ràn fún àwọn ohun-èlò ìpinnu olókè àti àwọn ará nígbà tí wọn bá béèrè
Yíyàn, ìdarapọ̀ àti àwọn ojúṣe
A ó yan àwọn ará ìgbìmọ̀ ní ètò ìdìbò ọdọọdún tí àwọn ará àjọṣepọ̀ ṣ’ètò. Àwọn olùdíje gbọdọ̀:
- Meet the Wikimedia Foundation's criteria for access to nonpublic personal data and confirm in their election statement they will fully comply with the criteria; and
- Kò gbọdọ̀ wà lábẹ́ ìjìyà iṣé-àkànṣe Wikimedia tàbí ìjìyà ìpàdé Kankan;
- Gbọ́ràn sí UCoC; àti
- Tẹ̀lé àwọn ohun àmúyẹ míràn tí ètò ìdìbò náà là kalẹ̀.
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ U4C gbọdọ̀ tọwọ́ bọ̀’wée àdéhùn àṣírí kí a tó fún wọn ní ànfààní láti wo àwọn ọ̀rọ̀ tí kò sí ní gbangba.
In exceptional circumstances, the U4C may call interim elections, in a format similar to that of the regular annual elections, if it determines that resignations or inactivity have created an immediate need for additional members.
Wikimedia Foundation lè yan bíí ọmọ ẹgbẹ́ àìdìbò méjì sórí ìgbìmọ̀ náà.
U4C le s’ẹ́dá ìgbìmọ̀ abẹ́ tàbí àwọn ènìyàn fún àwọn iṣẹ́ tàbí ojúṣèe pàtó gẹ́gẹ́ bí ó ti yẹ.
Membership in the U4C shall be open to any Wikimedia Movement community member in good standing. The U4C’s membership should be reflective of the global and diverse makeup of our global community.
Individual members of the U4C do not have to resign from other mandates (eg. local sysop, member of ArbCom, event safety coordinator), but they may not participate in processing cases they have been involved in as result of their other mandates.
Àwọn ìlànà
The U4C will decide on how often it should convene and on other procedures. The U4C may create or modify their procedures as long as it is with-in their scope. Where appropriate, the Committee should invite community comment on intended changes prior to implementing them.
Òfin àti ìṣẹ̀lẹ̀ ìtàn
U4C kò ní s’ẹ̀dá òfin titun , kò sì ní ṣ’àtúnṣe tàbí àyípadà sí Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí. U4C yíò yálà ṣe ìgbófìnró UCoC gẹ́gẹ́ bí àlàà rẹ̀.
While the Committee will typically take into account its earlier decisions when deciding new cases, previous decisions do not create precedent. As community policies, guidelines and norms evolve over time, previous decisions will be taken into account only to the extent that they remain relevant in the current context.
Ẹgbẹ́ Ìṣẹ̀dá U4C
Following ratification of the UCoC enforcement guidelines, the Wikimedia Foundation will facilitate a process to draft, in the form of a constitution, the remainder of the U4C process, handle any other logistics necessary to establish the U4C, and help facilitate the initial election procedures.
The Building committee will consist of volunteer movement members brought in through an open application process, affiliate staff volunteering for it and qualified Foundation staff based on specific skills (including legal experience, diversity & inclusion experience, and translatability expertise). Members will be selected by the Vice President of Community Resilience and Sustainability of the Wikimedia Foundation. Volunteer members for the committee will be respected community members with at least two of the following skills or traits:
- experience in policy drafting
- experience with the application of existing rules and policies on Wikimedia projects
- experience in cooperating online
- empathy
- experience in collaborating in an international team
- participatory decision making
They will be selected as much as possible to also represent the diversity of our movement in respect to languages spoken, geography, gender, age, project size of their home wiki, and their roles within the Wikimedia movement.
The work of the U4C Building Committee will be ratified either by the Global Council or by a community process similar to the ratification of this document.
Àtòjọ ìtúmò ọ̀rọ̀
- Alákoso (syop tàbí admin)
- Wo ìtúmọ̀ lórí Meta.
- Advanced rights holder
- user who holds administrative rights above typical editing permissions, generally elected through community processes or appointed by Arbitration Committees. This includes, as a non-exhaustive list: local sysops / administrators, functionaries, global sysops, stewards.
- Affiliations Committee tàbí Affcom
- Wo ìtúmọ̀ lórí Meta.
- Arbitration Committee or ArbCom
- group of trusted users who serve as the final decision making body for some disputes. Each ArbCom's scope is defined by its community. An ArbCom may serve more than one project (e.g. Wikinews and Wikivoyage) and/or more than one language. For the purposes of these guidelines, this includes the Code of Conduct Committee for Wikimedia Technical Spaces and administrative panels.
- Community
- Refers to a project’s community. Decisions made by a project’s community are generally determined by consensus. See also: Project.
- Community body
- Any collective decision body other than the U4C (for example a local or shared ArbCom, or a panel of local sysops).
- Re kọjá wiki
- Ohun tí ó kan iṣẹ́-àkànṣe tó ju ọ̀kan lọ. Tún wo: Àgbáyé.
- Event safety coordinator
- a person designated by the organizers of an in-person Wikimedia-affiliated event as responsible for that event’s safety and security.
- Àgbáyé
- Tọ́kasí gbogbo àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia.
- Àwon syop àgbáyé
- Wo ìtúmọ̀ lórí Meta.
- High level decision making body
- A group (i.e. U4C, ArbCom, Affcom) beyond which there can be no appeal. Different issues may have different high level decision making bodies. This term does not include a body of users participating in a discussion organized at a noticeboard and resulting in a decision, even if the results of that discussion cannot be appealed.
- Ìbílẹ̀
- Tọ́kasí iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia kan ṣoṣo.
- Mediation
- A formal process led by a mediator that attempts to resolve an issue without formal sanctions. The structure for mediation may be different in different places.
- Officer of a Wikimedia affiliate
- Any person in a decision-making role for any Wikimedia affiliate or who represents that affiliate.
- wiki ìkọ̀kọ̀
- wiki tí Wikimedia Foundation kò ni.
- Iṣẹ́-àkànṣe (Iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia)
- Wiki tí WMF n ṣ’àmójútó ẹ̀.
- Systematic issue
- An issue for which there is a pattern of failing to follow the Universal Code of Conduct with participation of several people, particularly such with advanced rights.
- Steward
- Wo ìtúmọ̀ lórí Meta.
- Related space hosted on third party platforms
- Websites, including private wikis, not operated by the WMF but where users discuss project matters relevant to Wikimedia. Often moderated by Wikimedia volunteers.