Wikimedia Foundation elections/2022/Translation/yo

This page is a translated version of the page Wikimedia Foundation elections/2022/Translation and the translation is 95% complete.

This page coordinates translation of the 2022 Board elections pages. The election committee will try its best to find many translators to reduce their individual workload. If you have any problems or questions about translation, please leave a message on Talk:Wikimedia Foundation elections/2022/Translation.

Ìtọ́sọ́nà ìdìbò

Ìdìbò yìí ó fi èsì àwọn olùdíje méjì tí a bá dìbò fún láti darapọ̀ mọ́ Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation.

 • Wàá rí àwọn àṣàyàn lórí ojú-ewé ìdìbò. Láti òkè ojú-ewé yìí, yan àwọn olùdíje ní bí o ṣe fẹ́ràn wọn sí, Lát'orí "Àṣàyàn 1" (ẹni tí o fẹ́ jùlọ) títí dé "Àṣàyàn 6" (ẹni tí o fẹ́ kẹ́yìn).
 • O kò nílò láti dìbò fún olùdíje kọ̀ọ̀kan. O lè dákẹ́ yíyàn tí àwọn tí o fẹ́ràn bá ti parí. Bí àpẹẹrẹ, o lè yan olùdíje kàn, tàbí mẹ́rìn, tàbí gbogbo wọn.
 • O lè ṣe àtúnṣe sí ìbò rẹẹ lákòkò ètò ìdìbò. Eléyìí yíò pa ìbò titẹ́lẹ̀ rẹ́. O lè ṣeléyì ní iye ìgbà tí ó bá wù ọ́.

Backup

Fún ìtọ́sọ́nà lórí bí o ṣelè dìbò nínú ètò ìdìbò yìí, wo ibí.

Candidate names

 • Farah Jack Mustaklem
 • Kunal Mehta
 • Michał Buczyński
 • Mike Peel
 • Shani Evenstein Sigalov
 • Tobechukwu Precious Friday

Other material

 • title: Ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation 2022
 • jumptext: Ìṣètò ìdìbò yìí ó wáyé lórí wiki ìṣọ̀kan. Jọ̀wọ́ tẹ bọ́tìnì ìsàlẹ̀ láti lọ síbẹ̀.
 • returntext: Ojú-ewé fún ìdìbò Wikimedia Foundation 2022
 • unqualifiederror: A tọrọ gáfárà, ṣùgbọ́n o kò sí lórí àtòjọ àwọn tó l'áṣẹ láti dìbò. Jọ̀wọ́ lọsí ojú-ewé ìrànlọ́wọ́ olùdìbò fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀rọ̀ lórí àṣe ìdìbò àti àlàyé lórí bí o ṣelè fọrúkọ s'órí àtòjọ olùdìbò tí o bá ní àṣẹ láti dìbò.
 • board elections title: Ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation 2022
 • candidates: Àwọn olùdíje