Movement Strategy/Updates/June 15, 2021/yo

This page is a translated version of the page Movement Strategy/Updates/June 15, 2021 and the translation is 47% complete.

Àwọn Ìjíròrò Kárí-ayé ti Strategy, 26-27 Oṣù Kẹ́fà

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjíròrò ló ti wáyé lórí Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀, òkúta igun-ilé ìsodàṣa Strategy Àjọṣepọ̀. Nítorípé a nílò láti bẹ̀ẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ lórí ìwé-àṣẹ pàtàkì yìí, à nya ipele ìjíròrò tó'kàn sọ́tọ̀ fún Ìgbìmọ̀ kíkọ Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀.

Movement Strategy/Events/Movement Charter Global Conversation, 26-27 June 2021/Movement Strategy Global Events Telegram group report

A dábàá:

  1. Láti dá àwọn ìjíròrò wọ̀nyí lóri ìbéèrè mẹ́tàa tí ó nílò ìdáhùn fún ìdásílẹ̀ ìgbìmọ̀ nọ́ọ̀.
  2. Láti bẹ̀rẹ̀ àwọn ìjíròrò lórí àwọn ìbéèrè wọ̀nyí lórí wiki àti àwọn pẹpẹ àwọn ará àjọṣepọ̀ míràn, ní oríṣiríṣi èdè.
  3. Láti ṣ'ètò àpèjọ àwọn ìjíòrò ìbílẹ̀ lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe, èdè, tàbí àgbègbè lórí àwọn ìbéèrè mẹ́tàa yìí ní òpin ọjọ́ Sátidé, 26 Oṣù Kẹfà, kí a sì pèsè ìjábọ̀ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.
  4. Láti ṣ'ètò ìpàdé ìjíròrò kárí-ayé ní Ọjọ́ Ìsinmi, 27 Oṣù Kẹ́fà fún ìbéèrè kọ̀ọ̀kan (ìṣẹ́jú 90).
  5. Láti gba àwọn èsì sílẹ̀ lẹ́yìn ipele yìí, kí a sì pèsè ìwe ìmọ̀ràn lórí ìṣẹ̀dá ìgbìmọ̀ kíkọ, fún ìpinnu àwọn ará àjọṣepọ̀.

Àwọn ìbéèrè tí a dá lábàá dá lórí àwọn ìjíròrò tí ó wáyé ní 12-13 Oṣù Kẹfà:

The Movement Charter drafting committee is expected to work as a diverse and skilled team of about 15 members for several months. They should receive regular support from experts, regular community reviews, and opportunities for training and an allowance to offset costs.

  • What composition should the committee have in terms of movement roles, gender, regions, affiliations and other diversity factors?
  • What is the best process to select the committee members to form a competent and diverse team?
  • How much dedication is it reasonable to expect from committee members, in terms of hours per week and months of work? Should the initial members commit for the whole duration of the project or should renewals be expected?

We are producing a short introduction to the Movement Charter and the context of these questions that will be published on Meta and translated to many languages. This intro should reflect the different perspectives and should allow most participants to form their opinions without having to dive into all the previous discussions. We want to make it easy for people to contribute answers to these questions.

The objective of this round of text and video conversations is to gather in-depth, diverse, quality feedback to support the next steps in the creation of the Movement Charter drafting committee.

The Movement Charter will define roles and responsibilities in the Wikimedia Movement, and it will lay out a new Global Council for movement governance. Join the text and/or video conversations and bring your perspectives!

Movement Strategy Global Conversations, June 12-13