Ètò ìdìbò ọdún 2018 ti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Yúróòpù.
In other languages
Ìmọ̀ nílò àṣẹ oníṣẹ́ ìgbàlódé tí ó bá lílò rẹ̀ lọ́fẹ́ lori Íntánẹ́ẹ̀tì mu.
Ìgbésẹ̀ tuntun tí ilé ìgbìmọ̀ aṣpòfin yúróòpù gbé nípa òfi tó dé iṣẹ́ oníṣẹ́ jẹ́ inira fún ààǹfàní tí àwọn èèyàn ní láti ṣe àpínlò ìfilọ̀.
Ní ọjọ́ karún oṣù keje ọdún 2018 ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin yúróòpù yío dìbò bóyá kí wọn ó tẹ̀síwájú lóri àṣẹ tuntun tí wọ́n fẹ́ pa lórí àṣẹ iṣẹ́ oníṣẹ́ tí ogúnlọgọ̀ ààjọ àti àwọn àjọ kọ́ọ́kan ní ilé ìgbìmọ̀ lòdì sí.
láti ọdún 2013, àwọn oníṣẹ́ àti ọmọ orílè èdè Yúróòpù tí sọfún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin yúróòpù wípé kí wọn ó ṣàtúnṣe sí òfin tí ó de iṣẹ́ oníṣẹ́ kí ó lè bá ti òde òní mu. Àwọn ẹgbẹ́ Wikimedia ní Yúróòpù ti gbé ìgbèsẹ̀ feasible proposals, bí kí àwọn èèyàn láàfàní láti lo iṣẹ́ tí ó ba ti wà ní gbangba ní ilẹ̀ yúróòpu kákàkiri láì gbàṣẹ lọ́wọ́ oníṣẹ́, léyìí tí ó maa ń ran oníṣẹ́ lọ́wọ́ láti gbẹ́ àwọn iṣẹ́ rẹ̀ jáde.
Ní ogúnjọ oṣù kẹfà, àjọ tó ń mójú tó òfin ní gbìmò láti tẹ̀síwájú́ pẹ̀lù ṣíṣòfin tí ó máa pín íńtánẹ́ẹ̀ti sí wẹ́lẹ́ wẹ̀lẹ tí ó sì máa kạwọ́ ará ìlù kò tí o jẹ́pé àwọn èèyan jàǹkọ̀ dìẹ láṣe.
A ní ìgbàgbọ́ wípé àwọn ará ìlú náà lè kópa nínú ìfọ̀rọ̀ jomitoro ló ìgbésẹ̀ àtunṣe sí òfin iṣẹ́ oníṣẹ́ yìí.
À pe gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Yúróòpù kí wọ́n díbò tako àkọsílẹ̀ yìí, kí wọ́n lo làákàyè nínú àtúnṣe yìí kí wọ́n ó fi ti àwọn èèyàn ṣe.
#SaveYourInternet
(Photo EP strasbourg by Alfredovic, 2010, Creative Commons BY-SA.)