Wikimedia Foundation elections/2021/Translation/yo

This page is a translated version of the page Wikimedia Foundation elections/2021/Translation and the translation is 97% complete.

The election ended 31 Oṣù Kẹjọ 2021. No more votes will be accepted.
The results were announced on 7 Oṣù Kẹ̀sán 2021. Please consider submitting any feedback regarding the 2021 election on the elections' post analysis page.

Ojú-ewé yìí wà fún ìṣètò ìtúmọ̀ fún àwọn ojú-ewé ìdìbò Ìgbìmọ̀ Onígbọ̀wọ́ 2021. Ìgbìmọ̀ ìdìbò yí ò ṣa ipá wọn láti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olùtúmọ̀ láti dín ẹrù iṣẹ́ kù. Tí o bá rí ìṣòro tàbí ìbéèrè kankan lórí ìtúmọ̀, jọ̀wọ́ kànsí wa lórí Talk:Wikimedia Foundation elections/2021/Translation.

2021 Board Elections
Main Page
Candidates
Voting information
Single Transferable Vote
Results
Discussions
FAQ
Questions
Organization
Translation
Documentation
This box: view · talk · edit

Ìtọ́sọ́nà ìdìbò

Ìdìbò yìí ó fi èsì àwọn olùdíje mẹ́rìn tí a bá dìbò fún láti darapọ̀ mọ́ Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation.

 • Wàá rí àwọn àṣàyàn lórí ojú-ewé ìdìbò. Láti òkè ojú-ewé yìí, yan àwọn olùdíje ní bí o ṣe fẹ́ràn wọn sí, Lát'orí "Àṣàyàn 1" (ẹni tí o fẹ́ jùlọ) títí dé "Àṣàyàn 19" (ẹni tí o fẹ́ kẹ́yìn).
 • O kò nílò láti dìbò fún olùdíje kọ̀ọ̀kan. O lè dákẹ́ yíyàn tí àwọn tí o fẹ́ràn bá ti parí. Bí àpẹẹrẹ, o lè yan olùdíje kàn, tàbí mẹ́rìn, tàbí gbogbo wọn.
 • O gbọdọ̀ yan àwọn olùdíje láì fo àwọn nọ́mbà kankan láàrín. Fífo nọ́mbà yí ò jásí èsì àṣìṣe. Fún àpẹẹrẹ:
  Àṣàyàn àkọ́kọ́: Ajá
  Àṣàyàn ìkejì: "(òfo)"
  Àṣàyàn ìkẹ́tàa: Olóngbò
 • A kò ní gba eléyì wọlé nítorí àṣàyàn ìkejì ṣ'ófo.
 • O kòle yan olùdíje kan ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà. Yíyan olùdíje kan ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà yí ò fi èsì àṣìṣe jáde. Fún àpẹẹrẹ:
  Àṣàyàn àkọ́kọ́: Ajá
  Àṣàyàn ìkejì: Ajá
  Àṣàyàn ìkẹ́tàa: Olóngbò
 • A kò ní gba eléyì wọlé nítorí o ti yan olùdíje "Ajá" léèmejì.
 • O lè ṣe àtúnṣe sí ìbò rẹẹ lákòkò ètò ìdìbò. Eléyìí yíò pa ìbò titẹ́lẹ̀ rẹ́. O lè ṣeléyì ní iye ìgbà tí ó bá wù ọ́.

Backup

Fún ìtọ́sọ́nà lórí bí o ṣelè dìbò nínú ètò ìdìbò yìí, wo ibí.

Candidate names

 • Adam Wight
 • Vinicius Siqueira
 • Eliane Dominique Yao
 • Victoria Doronina
 • Dariusz Jemielniak
 • Lionel Scheepmans
 • Reda Kerbouche
 • Rosie Stephenson-Goodknight
 • Mike Peel
 • Lorenzo Losa
 • Raavi Mohanty
 • Ashwin Baindur
 • Pavan Santhosh Surampudi
 • Ravishankar Ayyakkannu
 • Farah Jack Mustaklem
 • Gerard Meijssen
 • Douglas Ian Scott
 • Pascale Camus-Walter
 • Iván Martínez

Other material

 • title: Ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation 2021
 • jumptext: Ìṣètò ìdìbò yìí ó wáyé lórí wiki ìṣọ̀kan. Jọ̀wọ́ tẹ bọ́tìnì ìsàlẹ̀ láti lọ síbẹ̀.
 • returntext: Ojú-ewé fún ìdìbò Wikimedia Foundation 2021
 • unqualifiederror: A tọrọ gáfárà, ṣùgbọ́n o kò sí lórí àtòjọ àwọn tó l'áṣẹ láti dìbò. Jọ̀wọ́ lọsí ojú-ewé ìrànlọ́wọ́ olùdìbò fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀rọ̀ lórí àṣe ìdìbò àti àlàyé lórí bí o ṣelè fọrúkọ s'órí àtòjọ olùdìbò tí o bá ní àṣẹ láti dìbò.
 • board elections title: Ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation 2021
 • candidates: Àwọn olùdíje