Wikimania 2023/Ipe fun awọn ifisilẹ eto

This page is a translated version of the page Wikimania 2023/Call for program submissions and the translation is 100% complete.

Wikimania 2023 Awọn ifisilẹ Eto Gbigbawọle

 

Ṣé o fẹ́ jẹ́ agbàlejò gẹ́gẹ́ bí ẹnìkan tàbí lákòókò ètò ìfojúhàn ní Wikimania 2023? Bóyá ìdágbálé ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́, ìfọ̀rọ̀wérọ̀ tó ń móríyá, ìṣèré aláfẹ́ kan, pósítà tí ó fani mọ́ra, tàbí ọ̀rọ̀ ìlanilọ́yẹ mánigbàgbé? Ààyè ṣí sílẹ̀ fún ìdájọ àwọn èròǹgbà títí di Oṣù Kẹ́ta Ọjọ́ 28. Ayẹyẹ náà yóò ní ìfijì òní-ẹ̀yà méjì, nítorí náà ààyè wà bákan náà fún ìdájọ àwọn ètò ìfojúhàn àti àwọn fọ́nrán ìkásílẹ̀. Tí o bá ní àwọn ìbéèrè kankan, jọ̀wọ́ darapọ̀ mọ́ ìfọ̀rọ̀wérọ̀ wa tí ó bọ̀ lọ́nà ní oṣù ọjọ́ 12 tàbí 19, tàbí ké sí wa nípa lílo ìtàkùn-ìfiránṣẹ́ lórí wikimania@wikimedia.org tàbí lórí ìkànnì Telegram. Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn lórí-wiki.

-Àwọn ọ̀wọ́-lábẹ́-ọ̀wọ́-tí-ń-ṣagbátẹrù ètò Wikimania