Yàrá ìkàwé Wikipédíà/Ìwé Ìróyìn/Oṣù keje - Oṣù kẹjọ ọdún 2017
Issue 23, June — July 2017
Ní ti ọ̀tẹ̀ yí a ṣe ìfilélẹ̀ káàdì Yàrá Ìkàwé tuntun, ìtẹ̀síwájú káàkàkiri àti pé bí bí a ṣe maa ń ṣe, fún àkójọpọ̀ àwọn ìròyìn àti àwọn ohun èlò tí ó ní ṣe pẹ̀lú yàrá ìkàwé tí wọn máa rí lò fún ìmọ̀ ìgbàlóde ti díjítà
Káàdi Yàrá ìkàwé
A ti darí àwọn ìforúkọsílẹ̀ ti Ggbogbo Èdè Gẹ̀ẹ́sì sí Ààye Yàrá ìkàwé Wikipédíà! Káádì yàrá ìkàwé yìí jẹ́ iriṣẹ́ kan gbọ̀n tí wọ́n lè lò láti forúkọ sílẹ̀ láti láàfàní sí àyèwò ọ̀fẹ́ ti ó wá láti ọwọ́ àwọn tí ó yàrá ìkàwé Wikipedia dòwò pọ̀. Wà wọlé pèlú orúkọ tí o maa n fi wọlé sí Wikipedia, ti o kò ní maa fi àwọn ohun ìdánimọ̀ niḱpa rẹ sílẹ̀ ní gbogbo ìgbà tí o bá ti fẹ́ wọlé, tí ó jẹ/ kió ó rọrùn fún àwọn olùkọ̀tàn àti àwọn adarí. Kí ọdún yìí tó parí, a maa gba fífí ohun ìdánimọ̀ sílẹ̀ láàyè ( léyí tí ó jẹ́ pé o lè lo orúkọ̀ tí o fi ń wọlé sí Wikipedia ní àànfàní sí ojú òpó àwọn tí a ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú(, tí ó sì jẹ́ kí wíwọlé rọrùn.
Lóṣu tó ń bọ̀, a máa ṣiṣẹ́ lórí bí ìlọsíwájú ṣe lè bá àwọn ètò wa, pẹ̀lú àti àtúnṣe tó péye sí ojú ewé wa. A maa tún wá bí a ṣe lè ṣe ètò ní Translatewiki.net kí a lè gbárùkú mọ́ àwọn oníṣẹ́ tí kò gbọ́ èdè gẹ̀ẹ́sì àti àwọn tí ó ń ba wa dòwòpọ̀.
Wo àwọn ohun èlò ribiribi yìí kí o sì fi orúkọ sílẹ̀ láti lo èyí tí ó bá lè ran kíkọ àyọkà ẹ lọ́wọ́
Ẹgbẹ́ olóòtu
Yàrá ìkàwé Wikipédíà ń ṣisẹ́ takuntakun láti jẹ́ kí ìbáṣepọ̀ tí ó péye wà láàrin Wikipédíà àti àwọn Yàrá ìkàwé. Èyí ló fá dídásílẹ̀ Ẹgbẹ̣́ àwọn olótú Yàrá ìkàwé Wikipédíà Lẹ́yìn tí ẹ gbọ́ lá ti ọdọ̀ wa, oríṣiríṣi àwọn nkan lótiṣẹlẹ̀. Lákọ́kọ́, ẹgbẹ́ yìí ti dí mímọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n forúkọsílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ìkan lára àwọn egbẹ́ tí alámójúto dámọ̀. Láti ìgbà yẹn àwọn 147 ni óti forúkọ̀ sílẹ̀ tí àwọn olùdásílẹ̀ rẹ̀ sì ti pàdé ní ẹ̀ẹ̀mejì. Ìpàdé ỳí ní wọn ti jíròrò nípa ìlọsíwájú ẹgbẹ́, àwọn tí ó maa ṣe olórí, idí tí wọ́n fi dá ̣gbẹ́ sílẹ̀ àti oun tí wọ́n máa dojúkọ ni wọ́n sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀. Ara èsì ìpàdé náà ni dídásílẹ̀ ọwọ́ Twitter @WikilibraryUG àti òpó YouTube Ẹgbẹ́ Yàrá ìkàwé Wikipédíà. Ibẹ̀ ni wọ́n tún ti jíròrò wípé kí wọ́n máa lo Wikipedia + Libraries Facebook group lọ, kí wọ́n sì ṣe àtúnṣe sí òpó ìjíròro Wikimedia & Libraries kí wọ́n sì máa lòó lọ. Àwọn olùdásílẹ̀ rẹ̀ máa pàdé lẹ́yìn Wikimania 2017, tí wọ́n sì ní ohun púpọ̀ láti ṣe.
Kákàkiri àgbáyé
Àwọn ẹ̀ka wa kákàkiri àgbáyé ń gbòòrò síi pẹ̀lú mímú ìlọsíwájú bá àwọn olótú wa tí wọ́n nílò oun ti ó lè mú iṣẹ́ wọ ya. Àwọn oríṣiríṣi àwọn ọ̀na ni a ti gbìyàjú lati ri wípé àwọn ẹ̀ka wa tí kìí ṣe èdè gẹ̀ẹ́sí ri àwọn oun mèremère tí à ń ṣe múlò.
- A ti dá ẹ̀ka Yàrá Ìkàwé Wikipédíà ti èdè Korea sílẹ̀, ọpẹ́ pàtàki fún àwọn olùdarí rẹ̀ -revi, Motoko C. K. àti 책읽는달팽.
- Ẹgbẹ́ olóòtú Wikimedia ti Tunisia, lara iṣẹ́ wọn ni Yàrá Ìkàwé Wikipédíà, ti gba olótù Wikipedia ti a maa ṣakápò ni Diocesan Library of Tunis àti ní National Library of Tunisia, thanks to Csisc and team.
- Láti jẹ́ kí ìbáṣepọ̀ tí ó péye àti àmójútó wà, àwọn alámójútó ní ẹ̀kà wa tt dá oríṣiríṣi ẹgbẹ́ si àwọn òpó ìjíròrò bíi òpó ìbára eni sọ̀rọ̀ tii àwọn Persia àti ti Yàrá Ìkàwe Wikipedia fún àwọn alámójúto ti China. Tí obá nífẹ́ sí dída irú ẹgbẹ́ yìí sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn alámójútó ẹ̀ka tìrẹ, jọ̀wọ́ kàn sí AVasanth (WMF).
- A fẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní yẹ́ àwọn alámójútó wa sí fún iṣẹ ribiribi wọn. Lati ìsisìhín, a máa ṣèto àti pé a ma máa fún awọn tí ó bá ṣiṣẹ́ jùlọ ní nkan (sítíkà, ìgò ìrọmi) látarí Ètò Ògo Alabójútó. Èyi jẹ́ ọ̀nà tí a fi lè fi ẹ̀mí ìmoore han fún iṣẹ́ takuntakun tí àwọn alámójúto wa n ṣe.
Ojú ewé tó ń tọ́ka sí: Ìdojú ìjà kọ of́utùfẹ́ẹ̀tẹ ìròhin, ìròhin irọ́, àti àifún ènìyàn ní àǹfàní sí ìmọ̀
Èyí tí a fàyọ láti àtẹ̀jáde Wikimedia tí Margarita Noriega, Wikimedia Foundation tẹ̀jáde ní iọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù keje ,Ọdún 2017
Àwọn èèyàn díẹ̀ ti fi ara gbá ìṣẹ̀lẹ̀ búburú tí ó ń wáyé látàri ìjà àìlóp[in bí ti Ingrid Betancourt did ní ọdú 2002, nígbà tí àwọn ológun Colombia (FARC) jí Àrẹ-ìgbà náà gbé fún odindi ọdún mẹ́fà gbáko. Ó wá ń gba àwọ tókù níyànjú láti dá ààbo bo ìmọ̀ ọ̀fẹ́ àti oun tí ó péye wọ́n lè lò fún ìmọ̀ gẹ́gẹ́ bi aláṣojú fún àlááfíà
Láìpẹ́ yìí Betancourt sọ fún Wikimedia Foundation wípé òun gbàgbọ́ wípé “nkan pàtaki ni ki a kéde ìmọ ọ̀fẹ́. ... Oun tí ó léwu ni ìrohìn irọ́. Ìtan káàkàkiri iru ìròhìn bẹ́ẹ̀ léwu. O lè fa ìdíwọ́ fún ìròyìn láti rí ẹ̀yin rẹ̀ .” Bí a ṣe n gba ìrohìn gbọ́ níṣe pẹ̀lú bí àwọn èèyàn ṣe rí ibi tí ó ti ṣẹ̀wá sí... Àwọn míràn lè dojú kọ oun tí wọ́n kọ látàri àti rí èrè, àwọn míran tọ́ka sí èyí ti ìjọba n mójúto , àwọn míran sọ wípé ìrohìn irọ́ ni okùnfà (àkọ́lé kan ní ìjíròrò tí ó wáyé ní Unifásítì Yale t́ àwọn agbẹjọ́rò Wikimedia Foundation kópa). Pẹ̀lú oríṣiríṣi nkan láti dojúkọ (tàbí pajúdé fún), ìròhin tí kò péye jẹ́ oun tí ó n fa ìdíwọ́ fún ìgbìyànjú latí mú ìdàgbàsókè bá ìmọ̀ tí ó péye kákààkiri àwujọ.
"Ìtan káàkàkiri ìròhin tí kò péye lóri òpó ń wáyé bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé oríṣiríṣi àwọn àjọ tí ó ń yẹ irọ́ sí òótọ̀ wò ń gbòòrò.: Kákiri gbogbo àgbáyẹ́, ó kéré jú ọgọ́rúnlẹ́ mẹ́fàdínlógụn “ àwọn tí ń yẹ irọ́ sí òótọ” n ṣiṣẹ́ ní orílẹ̀ èdè mẹ́tàdín láàdọ́ta.
Wíwo ọjọ́ wájú, ki ni oun tí kò léwu tí a lè máa retí? Àkọ́kọ́, òmìnira kákàkiri àgbáyé láti sọ ọ̀rọ̀ yío gbòòrò tí ó sì ní ṣe pẹ̀lú ìdàgbàsókè òṣèlú orilè èdè kan àti kákààkiri. Èyí tí kò yéwa ni bóyá ìwà ìjẹgàbà máa dẹ́kun - tàbí, àwùjọ máa ṣe àtúnṣe, dàgbàsókè pẹ̀lú títiraka láti ri pé àwọn elétò ìròỳin ṣe òtítọ kí wọ́n si rí rírọ̀ ìròhin mọ́ òṣèlú bi àíṣòdodo irú ẹni bẹ́ẹ̀.
Ìkejì, a lè ròó wípé ìkéde ìròhin ìṣni lọ́nà àti èyí tí ò péye máa wà pẹ̀lú wa. Nítòótọ́, a lè ro tí a ń pè ní “ìròhìn irọ́,” ìròhin ìṣni lọ́nà, or “irọ́ funfun” pé ó ti wà láti ìḅ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, ti a sì lè fa àpẹerẹ yọ́ láti ìgbà ìwásẹ̀
wọn èèyan Wikimedia gbúdọ̀ múra àti pé àwọ olótú gbọ́dọ̀ wo oríṣirísí ọ̀nà ti ìmọ̀ fi lè ṣini lọ́nà tàbí jẹ́ irọ́ pọ́nbélé. Ó ṣe pàtàki kí wọ́n ṣe àkíyèsí kí wọ́n sì fi ojú sí àwọn ọ̀nà tí àwọn oníròyìn àti aṣèwádi fi ń se àrídájú pé òótọ ní ìmọ̀, bi èyí tí wọ́ ṣàpèjúwe rẹ̀ ní Ìwé Àyẹ̀wò, tí ó wà ní oríṣiríṣi èdè.
Àwọn ìdíwọ̀n lẹ́kunrẹ́rẹ́
- The Metropolitan Museum of Art: fún wa lánfàní sí ojú fèrèsé 375,000 tí ó dá lóri ìtàn ọnà, ti ó sì jẹ́ wípé wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ń mẹ́yẹ bọ̀lápò ni
- Bí a ṣe ṣe ìwárí àti bí ìmọ̀ tí ó péye ṣe ṣẹ̀ wá
Ìròhin tó péye
- Ìwádí nípa ìròhin ìmọ̀ Wikipedia
- Ilé ìwé àmòfin ti Yale àti Wikimedia Foundation ti dá ìwádí tuntun tí ó dá lóri bi a ṣe lètọ́jú àt dá ààbò bo ànfàní sí ìmọ̀ ọ̀fẹ́ lórí òpó
Library of Congress sí kátálọ́ọ̀gù fún gbogboògbò. Ìdí nìyí ti ó fi wúlò]
Éṣé fún kíkà! Láti máa gba ìròhìn olóṣoosù lóri ọ̀rọ̀ oníṣẹ́ rẹ nípa ọ̀tun Àwọn ìwé àti Ìdíwọ̀n, jọ̀wọ́ fi orúkọ rẹ sílẹ̀ sí
àkójọpọ̀ àwọn tó forúkọsílẹ̀. Tí o bá fẹ́ kí a fi ìròhìn ṣọwọ́ sí ẹ, jọ̀wọ fi orúkọ sílẹ̀ níbí. Tí obá fẹ́ gbàwà ní ìmọ̀nran lórí ìpele tóń bọ̀, jọ̀wọ́ kàn sí olótú, The Interior (talk · contribs) fún Ìmọ̀ràn.