Ìpè fún ìjábọ̀ awọn Ìgbìmọ̀ Adarí
Outdated translations are marked like this.
Ikọ̀ ìgbìmọ̀ adarí: Àríwòye yín ṣe pàtàkì
Àwùjọ awọn ikọ̀ ajọ WMF ni ó ń ṣe agbátẹrù fún dídá ìgbmọ̀ ikọ̀ awọn adarí jákè-jádò agbáyé. Ìdí tí wọ́n fi dáa sílẹ̀ ni wípé kí wọ́n lè ma gba awọn adarí gbogbo nímọ̀ràn lẹ́nu iṣẹ́ wọn.
Ikọ̀ ìgbìmọ̀ yí ń fẹ́ kí a ṣe àríwísí lórí iṣẹ́ ikọ̀ náà. Ojú-ewé Meta yí Leadership Development Task Force àti bí o lè ràn wá lọ́wọ́. Èsì abọ̀ ni a ó ma gbà láti ọjọ́ keje sí ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2022.