Koodu Iwa ti gbogbo agbaye/Awọn itọnisọna imuse / Idibo / Awọn itumọ
This page coordinates translation of the 2023 Universal Code of Conduct Enforcement Guidelines Ratification poll question.
Want to help translate? Translate the missing messages.
Dìbò
Bẹ̀ẹ́ni
Bẹ̀ẹ́kọ́
Ìbéèrè
Ǹjẹ́ o f'aramọ́ ìmúṣẹ Òfin Ìhùwàsí Àgbáyé lórí àwọn ìlànà ti a gbèrò náà?
Ìdìbò yìí jẹ̀ ara ètò ìfọwọ́sí fún àwọn ìlàna ìfọwọ́sí ti Òfin Ìhùwàsí Àgbáyé. Fi ìbò rẹ sí ìsàlẹ̀ yìí. Fún ìwífún síi, kàn sí ojú-ewé ìrànwọ́ olùdìbò lórí Meta-Wiki.
Jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé "Bẹ́ẹ̀kọ́" tàbí "Bẹ́ẹ̀ni". Dibo pẹ̀lú yálà "Bẹ́ẹ̀kọ́" tàbí "Bẹ́ẹ̀ni" a kò ní ṣe àfihàn èyí tí ẹ yàn ní ibi òǹkà àṣẹkágbá
A ó ṣe àkópọ̀ àwón àlàyé a ó sì gbé e sórí wiki láì s'àfihàn ìwífún ìdánimọ̀.
Other material
- title: Ìṣekádìí àwọn Ìlàna Ìfọwọ́sí ti Ìgbẹ Òfin Ìhùwàsí Àgbáyé rọ.
- jumptext: Ìbò náà yóò wáyé lórí ààrin gbùngbùn wiki kan. Jọ̀wọ́ tẹ bọ́tìnì náà n'ísàlẹ̀ láti fi ránṣẹ́. Jọ̀wọ́ ríi pé nígbà tí o bá dibò ìwífún kan tí ó ní àdírẹ́sì IP rẹ tí asojú ìlò yoo jẹ́ gbígbà lati gba àwọn olùyẹ̀wọ̀ láàyẹ̀ lati s'àrídájú jíjẹ́ òótọ́ ìbò náà. Ìwífún náà yoo jẹ́ píparẹ́ ní ọjọ́ 90 lẹ́yìn ti ìdìbò bá parí yóò sí ṣeé rí fún àwọn olùyẹ̀wọ̀ àti àwọn olùdámọ̀ràn òsìṣẹ̀ ìdìbò nìkan.
- returntext: Iṣẹ́ Òfin Ìhùwàsí Àgbáyé
- unqualifiederror: A tọrọ gáfárà, ṣùgbọ́n o kò sí lórí àtòjọ àwọn tó l'áṣẹ láti dìbò. Jọ̀wọ́ lọsí ojú-ewé ìrànlọ́wọ́ olùdìbò fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀rọ̀ lórí àṣe ìdìbò àti àlàyé lórí bí o ṣelè fọrúkọ s'órí àtòjọ olùdìbò tí o bá ní àṣẹ láti dìbò.