Àgbéyẹ̀wò Òfin àti Àlàkalẹ̀ Gbogbo gbòò

This page is a translated version of the page Universal Code of Conduct/Policy text and the translation is 16% complete.
Outdated translations are marked like this.
Other languages:
Bahasa Indonesia • ‎Bahasa Melayu • ‎Chi-Chewa • ‎Deutsch • ‎English • ‎Esperanto • ‎Hausa • ‎Igbo • ‎Kiswahili • ‎Kreyòl ayisyen • ‎Luganda • ‎Nederlands • ‎Setswana • ‎Tiếng Việt • ‎Türkçe • ‎Yorùbá • ‎azərbaycanca • ‎català • ‎eesti • ‎español • ‎français • ‎isiZulu • ‎italiano • ‎magyar • ‎polski • ‎português do Brasil • ‎română • ‎suomi • ‎svenska • ‎čeština • ‎Ελληνικά • ‎русский • ‎українська • ‎հայերեն • ‎עברית • ‎العربية • ‎فارسی • ‎नेपाली • ‎मराठी • ‎हिन्दी • ‎বাংলা • ‎ગુજરાતી • ‎தமிழ் • ‎తెలుగు • ‎ไทย • ‎ქართული • ‎中文 • ‎日本語 • ‎한국어

Why we have a Universal Code of Conduct

Òfin àti Àlàkalẹ̀ gbogbo gbò (UCoC) ni ó ṣe àlàpín sí àwọn ìwà tí ó tọ̀nà àti àwọn ìwà tí kò bójú mu. Òfin yí de gbogbo ẹnikẹ́ni tí ó bá ti ní nkan ṣe pẹ̀lú iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia, yálà lórí.òpó ayélujára ni tabí ní ojúkojú. Òfin yí bá àwọn akópa titun tàbí àwọn tí wọ́n ti pẹ́ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ kan tàbí òmíràn fún Wikimedia.

A fẹ́ mí àwùjọ wa ó dára, kí ó láàbò kí ó sì wà ní àláfía fún ẹnikẹ́ni ti ó bá fẹ dara lọ̀ mọ. Bákan náà, a tún fẹ́ dáàbò bo iṣẹ́ àkànṣe.wa gbogbo lọ́wọ́ àwọn ọ̀bàyéjẹ́ kí wọn ó má lè daaru.

Àwọn òfin gbogbo gbò tàbí òfin kárí-ayé yí ni ó mú tàbí de tẹrú-tọmọ láì yọ ẹnìkan kan sílẹ̀ nínú àjọ Wikimedia jákè-jádò agbaiye. Tírtàpá sí òfin yí lè mú ìjìyà tí o gbópọn dání láti ọwọ́ àwọn ìg ìmọ̀ amúṣẹ́ṣe Kógbérèégbè Wikimedia tàbí láti ọwọ́ àwọn eka won gbogbo.

Ní ìbámu pẹ̀lú àfojúsùn àjọ Wikimedia, gbogbo ẹni tí o bá ti ń kópa nínú iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia yóò ni:

 • Lè sapá láti dá àwùjọ tí ẹnìkẹ́ni yóò ti lè ṣàfikún tàbí jẹ́ olùpín nínú ìmọ̀ kan tàbí òmíràn bí o tilẹ̀ wù kí o kéré tó.
 • Lè kopa nínú awujo Wikimedia lágbàáyé láì fi ti eyaẹ̀yà, èdè láì ní àbòsí kankan nínú.
 • Lè sapá láti já fáfá kí o fi ìdí iṣẹ́ rẹ̀ múlẹ̀ ní gbogbo ọnà.

1 – Introduction

Lará rẹ̀ ni :

 • Ìbáṣepọ̀ àwùjọ kékèké àti ńlá.
 • Ìyapa ẹnu lórí ọ̀rọ̀ tí ó lè mú ìdàgbà-sókè tó peregedé bá àwùjọ Wikimedia àti àwọn ènìyàn ibẹ̀.
 • Àwọn ọ̀rọ̀ lórí ìdàgbà-sókè ọ̀nà ìgbàṣisẹ́
 • Ọ̀rọ̀ tí ó dá lórí ṣíṣe àfikún àwọn àkòrí.
 • Ìlànà bí àwọn ẹ̀ka aṣoju Wikimedia ṣe lè ṣojú wọn lọ́dọ̀ àwọn alábàáṣe wọn láti ìta
 • Ìbáṣepọ̀ gbogbo gbò, ìbá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ àti ìṣesí pẹ̀lú àwùjọ àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́.

The Universal Code of Conduct applies equally to all Wikimedians without any exceptions. Actions that contradict the Universal Code of Conduct can result in sanctions. These may be imposed by designated functionaries (as appropriate in their local context) and/or by the Wikimedia Foundation as the legal owner of the platforms.

Òfin àti àlàkalẹ̀ kárí-ayé yí lórí ìgbésẹ̀ ìbáṣepọ̀ lórí awoin iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia lọ́kan ò jọ̀kan káàkiri àgbáyé. Àwọn ẹ̀ka aṣojú Wikimedia kaakiri àgbáyé lè ṣe àfikún sí òfin yí nípa wíwo ṣakun àṣà, ìṣe abínibí wọn ní ìlànà tí òfin náà fi lè bá àwùjọ tiwon mu. Àmọ́, wọ́n ní láti ṣe èyí nípa títẹ̀lé ìlànà bí àjọ Wikimedia ṣe ṣagbékalẹ̀ òfin náà lọ́nà to peregedé.

Gbogbo òṣìṣẹ́, yálà wọ́n ti pẹ́ ni tàbí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ forúkọ sílẹ̀ ni, àwọn abẹnugan àjọ Wikimedia, àwọn ẹ̀ka tàbí àwọn ìgbìmọ̀ Wikimedia, gbogbo wọn pátá ni won yóò jíyìn fún iṣẹ́ wọn

Ìwà ìbọ̀wọ̀-fún, ìmẹ̀tọ́, ìbáṣepọ̀ tó lọ́ọ̀rìn , ìṣọ̀kan àti ìjẹ́ ẹni rere ni a ń retí lọ́wọ́ àwọn olùkópa nínú gbogbo iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia pátá jákè-jádò àgbáyé. Àwọn ìwà wọ̀nyí ni a gbọ́dọ̀ ma gbóòórùn rẹ̀ lará àwọn oníṣẹ́ aláfikún pátá láì kọyán ẹnìkan kéré nípa àì má ṣe àmúlò ẹlẹ́yà-mẹ̀yà, lílo ọjọ́-ori, ìṣesí, ìrísí, ẹ̀sìn, ìdẹ́yẹsíni, lilo ipò, mímọ̀rọ̀'sọ, lílo ìjákọ tàbí ìjábo, lílo ìmọ̀ tàbí iṣẹ́ tàbí ìpèníjà ara.

2.1 – Mutual respect

Ìwà ìbọ̀wọ̀ fúni jẹ́ bíbu ọlá fún ẹlòmíràn. A ní láti máa bọ̀wọ̀ fún ara wa gẹ́gẹ́ bí a ṣe fẹ́ kí wọ́n o bọ̀wọ̀ fún àwa náà, yálà ní ibi iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia lórí ẹ̀rọ ayélujára ni tàbí ní ojúkojú.

Lará rẹ̀ tún ni:

 • *Lílo ìgbọ́ra-ẹniyé. Fara balẹ̀ gbọ́ ohun tí ẹnikẹ́ni nínú àwọn akẹgbẹ́ rẹ tí wọ́n jẹ́ onise Wikimedia ba fẹ́ sọ fún ọ. Gbaradì láti lo ìmọ̀sílára àti àgbọ́yé rẹ lórí ohun tí o ń retí gẹ́gẹ́ bí oníṣẹ́ Wikimedia.
 • Jẹ́ kí ọkàn rẹ ó mọ́, kí o sì sọ̀rọ̀ pẹ̀lú àròjinlẹ̀. Fèsì sí ọ̀rọ̀ pẹ́lú ẹ̀mí kan. Bí o bá ní ìyapa èrò lórí ọ̀rọ̀ kan, gbé ọ̀rọ̀ náà kalẹ̀ pẹ̀lú àròjinlẹ̀,lo àwọn ọgbọ́n tí ó tọ́ láti mú ìlọsíwájú bá ìyapa ẹnu rẹ.
 • Bọ̀wọ̀ fún bí àwọn oníṣẹ́ bá ṣe pe orúkọ tàbí ṣàpèjúwe ara wọn. Àwọn ènìyàn lè lo onírúurú ìlànà láti ṣàpèjúwe ara wọn. Gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ ìbọ̀wọ̀ fún, lo ìlànà tí wọ́n bá fi pe ara won gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe lòó nígbà tí o bá ń bá wọn sọ̀rọ̀ tàbí sọ̀rọ̀ nípa wọn lẹ́yìn. Bí àpeere:
 • Awon eya kan le lo leta, ohun,tabi oro kan lati inu ede won ti yoo sajoji si iwo;
  • Awon eniyan ti a mo dara dara tun le lo oruko tabi aropo oruko;
  • Awon eniyan ti won ni ipenija ara kan tabi omiran le lo ohunkohun lati fi juwe ara won.
 • Bi a ba pade ara, a o gbiyanju lati ki gbogbo wa ju abo, a o si ri wipe a bu ola fun gbogbo wa kari kari ni gbogbo ona.
 • Assume good faith, and engage in constructive edits; your contributions should improve the quality of the project or work. Provide and receive feedback kindly and in good faith. Criticism should be delivered in a sensitive and constructive manner. All Wikimedians should assume unless evidence otherwise exists that others are here to collaboratively improve the projects, but this should not be used to justify statements with a harmful impact.
 • Respect the way that contributors name and describe themselves. People may use specific terms to describe themselves. As a sign of respect, use these terms when communicating with or about these people, where linguistically or technically feasible. Examples include:
  • Ethnic groups may use a specific name to describe themselves, rather than the name historically used by others;
  • People may have names that use letters, sounds, or words from their language which may be unfamiliar to you;
  • People who identify with a certain sexual orientation or gender identity using distinct names or pronouns;
  • People having a particular physical or mental disability may use particular terms to describe themselves
 • During in-person meetings, we will be welcoming to everyone and we will be mindful and respectful of each others’ preferences, boundaries, sensibilities, traditions and requirements.

2.2 - Ìwà Ẹ̀tọ́, Ìfọwọ́sowọ́pọ̀, Ìṣọ̀kan àti ìjẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè rere

Iwa Eto ni ki eniyan o mo iwa, oro ati isesi ti o to laarin awujo kan. Ifowosowopo ni ikunra-eni lapa tabi asa iranra-eni lowo lati le se ohun kan laseyori. Ije omo orile-ede rere ni ki a ri wipe gbogbo ise akanse Wikimedia pata n so eso rere, ki o dun un se, ki o si je awujo ti o lalaafia lati darapo mo nigba kuu gba.

 • Civility is politeness in behaviour and speech amongst people, including strangers.
 • Collegiality is the friendly support that people engaged in a common effort extend to each other.
 • Mutual support and good citizenship means taking active responsibility for ensuring that the Wikimedia projects are productive, pleasant and safe spaces, and contribute to the Wikimedia mission.

Lará rẹ̀ náà tún ni:

 • Jẹ́ Atọ́nà àti Olùkọ́. Ran ènìyàn tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ dara pọ̀ mọ́ Wikimedia lọ́wọ́ láti ní ìmọ̀ kíkún lórí bí Wikimedia ṣe ń ṣiṣẹ́.
 • Fi ìṣòkan hàn. Máa bèrè àwọn oníṣẹ́ bíi tìrẹ lóòrè-kóòré, ran wọ́n lọ́wọ́ nígbà kúùgbà tí wọ́n bá nílò ìrànwọ́ rẹ, kí o sì jà fita-fita fún wọn bí wọ́n bá fi ẹ̀gbin kan kàn wọ́n tí ó lòdì sí òfin àti ìlànà Wikimedia.
 • Mentorship and coaching: Helping newcomers to find their way and acquire essential skills.
 • Looking out for fellow contributors: Lend them a hand when they need support, and speak up for them when they are treated in a way that falls short of expected behaviour as per the Universal Code of Conduct.
 • Recognize and credit the work done by contributors: Thank them for their help and work. Appreciate their efforts and give credit where it is due.

3 – Unacceptable behavior

Ṣíṣòfin kárí-ayé yí ni yóò ràn gbogbo eni tí ó bá ti ń ṣe àfikún kan tàbí òmíràn sí orí iṣẹ́ àkànṣe wikimedia lápapọ̀ lọ́wọ́ láti lè ṣe àdáyanrí àti ṣe ìyàtọ̀ láàrín ìwà ẹ̀tọ́ àti ìwà kò tọ́ tí ó burú jái, tí o sì lè mú ìdójútì wá fúni. Àwọn ìwà wọ̀nyí ni a lè pè ní ìwà kò tọ́ láàrín àwùjọ Wkimedia.

3.1 – Harassment

Iwa itenimere ni ki a moomo yepere, foju pani re tati mu eni binu lona ti ko dara. A le so wipe iwa kan je iwa itenimere nigba ti o ba ti koja ohun ti eniyan le gba mora. Iwa itenimere tun le waye nigba ti won ba n fi ohun ti o duni se yeye, paa paa julo si eni ti ko lagbaja.

 • *Egbin tabi Iwosi: Eyi le jasi wipe ki won peni louko koruko, nipa fifi eebu ara buni. Egbin tabi iwosi ni a le pe ni bi enikan se n ronu, bi o se ri, eya ati iran ti o je, irufe esin ti o n sin, bi asa ati ise re se ri,yala ako ni tabi abo,ojo ori re ni tabi ipenija ara ti o ni ni, tabi awon nkan miiran ni o nise pelu eyan. Lopo igba, yiyeye eni,ifini rerin tabi ifajuro sini lera lera si elomiran le tumo si iwosi tabi egbin, koda, bi a ko ba tile fenu so.
 • Ifipa bani lopo: Ibalopo ti ko wa lati inu eni tabi ki a soro sakasaka si elomiran.
 • Idunkoko moni: Hilale moni loju koju, lilo ofin,ifiya-jeni lona aito tabi ki a se ohun kan ti ko da ti o le mu elomiran huwa lona ti o fe.
 • Gbigbimo ika fun elomiran: Eyi le je nipa ki a gba elomiran ni iyanju lati gbemi ara re, se jamba fu ara re, tabi ki a gba elomiran ni iyanju lati se ika fun elomiran.
 • Isatojubo: Eyi ni ki a fi awon asiri ikoko eni kan bii: e-mail, iwe, oruko irisi, ile-ise enikan lede lai gba ase lowo onitohun lati se bee. Ewo ni ki enikeni o safihan tabi fi ohun kan ti elomiran fi pamo lede sori ero ayelujara. Pupo lara awon eka Wikimedia le ma fi awon ohun kan tabi omiran si ori itakun ayelujara, amo ki won ko lati se akosile re si ori ise akanse Wikimedia gbogbo.
 • Sisoni lowo lese: Eyi ni ki enika o ma so elomiran kaakiri gbogbo ibi ti o ba ti n sise lete ati le bu enu ate lu ise onitohun ki won le kuna tabi pofo lori ise ti won ba be.
 • Itakoni: Irufe iwa yi ni ki enikan o moomo ma funi laye lati so ero tire tabi ma ko ni elomiran lona ti ko bojumu lete ati mu inu bi onitohun.
 • Sexual harassment: Sexual attention or advances of any kind towards others where the person knows or reasonably should know that the attention is unwelcome or in situations where consent cannot be communicated.
 • Threats: Explicitly or implicitly suggesting the possibility of physical violence, unfair embarrassment, unfair and unjustified reputational harm, or intimidation by suggesting gratuitous legal action to win an argument or force someone to behave the way you want.
 • Encouraging harm to others: This includes encouraging someone else to commit self-harm or suicide as well as encouraging someone to conduct violent attacks on a third party.
 • Disclosure of personal data (Doxing): sharing other contributors' private information, such as name, place of employment, physical or email address without their explicit consent either on the Wikimedia projects or elsewhere, or sharing information concerning their Wikimedia activity outside the projects.
 • Hounding: following a person across the project(s) and repeatedly critiquing their work mainly with the intent to upset or discourage them. If problems are continuing after efforts to communicate and educate, communities may need to address them through established community processes.
 • Trolling: Deliberately disrupting conversations or posting in bad-faith to intentionally provoke.

3.2 – Abuse of power, privilege, or influence

Eniyan le si agbara lo nigba ti o ba fi ola ipo re se igberega, huwa buburu tabi ki o ma fipo ba awon eniyan ja. Ninu ajo Wikimedia, o saba ma n waye ni ona ijeni-nipa lona bi (itakuroso tabi ilo laakaye eni) ti o si le mu ifegbin kani lowo.

 • Sisi ipo awon alase ati osise lo: Sisi ipo, imo tabi awon ohun elo ti o wa ni arowoto awon alase, bakan naa ni awon osise ajo Wikimedia tabi awon asoju Wikimedia ni orile-ede kookan le lo ipo won lati fi hale mo akegbe won tabi ki won tile fi se imo tara-eni nikan.
 • Sisi ipo asiwaju ati imoni lo: Lilo ipo tabi oruko eni lati fi te elomiran mere. A ma n ba awon ti won ni iriri repete wipe ki won se medo nitori wipe biw won ba le fi ejo iwa kiwa kan nipa won sun, o le fun won nikun.
 • Ikefin si: Bi a ba n sise pelu opo eniyan, paa paa julo awon asoju Wikimedia lore ede kookan ni won ko gbodo huwa ti awon omoleyin won fi gbodo ma fura wipe won ko sotito, won ko si gbodo ba enikeni ti o ba tako aba won ja
 • Abuse of office by functionaries, officials and staff: use of authority, knowledge, or resources at the disposal of designated functionaries, as well as officials and staff of the Wikimedia Foundation or Wikimedia affiliates, to intimidate or threaten others.
 • Abuse of seniority and connections: Using one's position and reputation to intimidate others. We expect people with significant experience and connections in the movement to behave with special care because hostile comments from them may carry an unintended backlash. People with community authority have a particular privilege to be viewed as reliable and should not abuse this to attack others who disagree with them.
 • Psychological manipulation: Maliciously causing someone to doubt their own perceptions, senses, or understanding with the objective to win an argument or force someone to behave the way you want.

3,3 -Bíba iṣẹ́ Àkànṣe jẹ́

Mi moomo lati ma safikun awon akori ti ko ye tabi ki akori ti ko fese mule si ori ikani Wikimedia gbogbo tabi ki enyan o ma di dida akori gidi tuntun miiran sile. lara re ni:

 • Mimoomo yo awon akori gidi ori kuro lai se iwadi ati orinkiniwin ayewo lori irufe akori bee boya o kan nile atunse ranpe kan ni saaju ki won to yoo danu.
 • Lilo ogbon ewe lati maa fi yi awon akori ti o fese mule kuro ni bi o se ye lete ati le fi gbe ero, ogbon tabi imo tara eni nikan leyin ko to
 • Siso oro kobakungbe si enikan, tabi opo eniyan kan lati le ma fi tabuku, da ija sile tabi lati fi ikoria re han si awon awujo eninyan kan, eya, esin, awo, tabi orile-ede ti won ti wa.
 • Lilo awon ami, aworan, tabi ohunkan tabi omiran lati le fi tabuku tabi ko ipalara ba awon elomiran ko to.
 • The repeated arbitrary or unmotivated removal of any content without appropriate discussion or providing explanation
 • Systematically manipulating content to favour specific interpretations of facts or points of view (also by means of unfaithful or deliberately false rendering of sources and altering the correct way of composing editorial content)
 • Hate speech in any form, or discriminatory language aimed at vilifying, humiliating, inciting hatred against individuals or groups on the basis of who they are or their personal beliefs
 • The use of symbols, images, categories, tags or other kinds of content that are intimidating or harmful to others outside of the context of encyclopedic, informational use. This includes imposing schemes on content intended to marginalize or ostracize.