Movement Charter/Drafting Committee/Announcement 2021 07 27/Short/yo

This page is a translated version of the page Movement Charter/Drafting Committee/Announcement 2021 07 27/Short and the translation is 75% complete.
Outdated translations are marked like this.

Ìpè fún Àwọn Ará Ìgbìmọ̀ Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀ Wikimedia

Strategy Àjọṣepọ̀ Wikimedia nṣe ìkéde ìpè fún àwọn ènìyàn láti fọrúkọ sílẹ̀ fún Ìgbìmọ̀ fún Kíkọ ti Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀. Ìpè yìí yíò sí sílẹ̀ ní Ọjọ́ kejì oṣù kẹ́jọ̀ọ, 2021, yíò sì parí ní ọjọ́ kíní oṣù kẹ́sàn, 2021.

Ẹgbẹ́ yìí yí ò ní àwọn ará 15. À nretí wípé ẹgbẹ́ yìí yíò jẹ́ asojú àwọn onírúurú ènìyàn tí ó wà káàkiri àjọṣepọ̀ yìí. Àwọn irú ẹ̀yà, èdè, orílẹ̀-èdè, àti ìrírí. Lára rẹ̀ ni ìkópa nínú àwọn iṣẹ́-àkànṣe, àwọn ẹ̀ka Wikimedia àti Wikimedia Foundation.

Njẹ́ o fẹ́ tẹ Wikimedia síwájú nípasẹ̀ ipò pàtàkì yìí? Fi orúkọ rẹ̀ẹ sílẹ̀ lát'ọ̀sẹ̀ tó nbọ̀ lọ níbí. Jọ̀wọ́ kànsí strategy2030 wikimedia.org fún ìbéèrè.