Community Wishlist Survey 2019/Banner/yo
Àwọn àtòjọ àgbéyẹ̀wò ètò àwùjọ wa
Fi èrò rẹ ṣọwọ́ lórí àwọn irinṣẹ́ Wíkì tuntun tàbí tI tẹ́lẹ̀!
Dìbò yan èyí tí ó bá wù ọ́ nínú àwọn àtòjọ àlàkalẹ̀ ètò àwùjọ wa
Ẹ ran àwọn ikọ̀ tí ó ń ṣe irinṣẹ́ àmúṣe-múlò àwùjọ lọ́wọ́ láti lè mọ̀ irúfẹ́ iṣẹ́ àkànṣe wo lókù fún wọn láti ṣe!
Dìbò yan iriṣẹ́ Wíkì tuntun tàbí ti èyíbtí a ṣàtúnṣe rẹ̀ tí ofẹ́ rí!