Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀/Ìgbìmọ̀ kíkọ/Ìtúmọ̀ fún Ìdìbò

This page is a translated version of the page Movement Charter/Drafting Committee/Election translation and the translation is 100% complete.

Ètò ìdìbò 2021 fún Ìgbìmọ̀ kíkọ ti Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀ Wikimedia

Ìdìbò yìí ó fi èsì àwọn olùdíje méjèe tí a bá dìbò fún láti darapọ̀ mọ́ Ìgbìmọ̀ kíkọ ti Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀ Wikimedia.